Ìṣiṣẹ́àbínimọ́

(Àtúnjúwe láti Gẹ́nẹ́tíìkì)

Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ tabi Gẹ̀nẹ́tíkì (lati Èdè Gíríìkì aye atijo, γενετικός genetikos, γένεσις genesis, “ibere”[1][2][3]) gegebi apa eko baoloji, je sayensi awon abimo, ijogun, ati iyasorisi larin awon adiarajo alaaye.[4][5]

Jíìnì.png

Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ da lori idimu ati imuse oniakinkinni awon abinimo, pelu iwa abinimo ninu ahamo tabi adirajo (f.a. ilagbaralori ati isiseabinimoju), pelu ogun latodo obi si omo, ati pelu ipinkari, iyasoto ati iyipada larin awon olugbe. Nitoripe awon abinibi wa ninu gbogbo awon adirajo alaaye, isiseabinibi se lo lati se akomo gbogbo awon sistemu alaaye, latori awon eran ati bakteria, de ori awon ogbin (agaga awon eso oko) ati awon eran osin, de ori awon eniyan (bi ninu isiseabinibi oniwosan).