Gbéringbérin je ohun yiowu ti ni papa gberigberin. Papa gberingberin yi ko se foju ri sugbon ohun ni un fa ini pataki gberingberin kan: agbara la ti fa awon eroja gberingberin ferro bi irin be ni o si un fa mora tabi sun sohun awon gberingberin miran.

Iron filings that have oriented in the magnetic field produced by a bar magnet


Itokasi àtúnṣe