George Clinton (olórin)
(Àtúnjúwe láti George Clinton (musician))
George Clinton (ojoibi July 22, 1941) je akorin, adaorin, olori egbe onilu, ati atokun orin ati eni pataki ninu idasile iru orin P-Funk ara Amerika. Ohun ni eni to se idasile awon He was the mastermind of the egbe onilu Parliament ati Funkadelic larin 1970 ati ibere 1980, to si bere si ni dakorin ni 1981. Won ti pe bi ikan ninu awon oludasile pataki orin funk, ohun ati James Brown ati Sly Stone. Clinton je sisafikun si Iyesi Olokiki Rock and Roll ni 1997
George Clinton | |
---|---|
George Clinton performing in 2007 | |
Background information | |
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Keje 1941 Kannapolis, North Carolina, United States |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Plainfield, New Jersey, United States |
Irú orin | Funk, soul, rock, funk rock, rhythm and blues |
Occupation(s) | Singer, songwriter, producer |
Instruments | Vocals, synthesizers, keyboard |
Years active | 1955–present |
Labels | Capitol Paisley Park/Warner Bros. Sony 550 Music/Epic The C Kunspyruhzy Shanachie |
Associated acts | Parliament Funkadelic Bootsy's Rubber Band |
Website | georgeclinton.com |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |