Giorgos Seferis
(Àtúnjúwe láti George Seferis)
Giorgos tabi George Seferis (Γιώργος Σεφέρης) ni orúkọ ìnagijẹ Geōrgios Seferiádēs (Γεώργιος Σεφεριάδης, 13 March [O.S. 29 February] 1900 - September 20, 1971). Òhun ni olùkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè Greece tó ṣe pàtàkìjùlọ ní bíi ogún ọrundún sẹ́yìn, tí ó gba ẹbun Nobel. Ó tún ṣisẹ́ bíi aṣojú orílẹ̀ èdè rẹ̀ ní Greek Foreign Service, kí wọ̣́n tó yànhán gẹ́gẹ́ bí asojú sí UK, ibi tó wà lati ọdún 1957 sí 1962.
Giorgos Seferis | |
---|---|
Fáìlì:Giorgos Seferis.jpg | |
Iṣẹ́ | Poet, Diplomat |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Greek |
Notable awards | Nobel Prize in Literature 1963 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |