Gladys Knight

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Gladys Maria Knight (ojoibi May 28, 1944), to gbajumo bi "Empress of Soul",[1][2] (Iyaluaye orin Soul)) je akorin, olukoweorin ato osere ara Amerika. O gba Ebun Grammy ni emeje,[3] Knight gbajumo fun awon ayori orin to gbejade ni igba ewadun 1960s ati 1970s, fun ile-ise agbeorinjade Motown ati Buddah Records, pelu egbe olorin re to unje Gladys Knight & the Pips, to ni egbon re Merald "Bubba" Knight ati awon iyekan re Edward Patten ati William Guest bi omo egbe olorin.

Gladys Knight
Knight in 1969
Knight in 1969
Background information
Orúkọ àbísọGladys Maria Knight
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiThe Empress of Soul
Ọjọ́ìbíOṣù Kàrún 28, 1944 (1944-05-28) (ọmọ ọdún 79)
Atlanta, Georgia, U.S.
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • actress
Instruments
  • Vocals
  • piano
Years active1953–present
Labels
Associated acts



Itokasi àtúnṣe

  1. "The Voice, Winter 2007, Society of Singer's 16th Ella Awards" (PDF). Singers.org. Archived from the original (PDF) on 2008-02-27. Retrieved 2015-08-18. 
  2. ""Empress of Soul" Gladys Knight will be giving a special performance at Morongo Casino, Resort & Spa, November 7". Braintrustlv.com. September 22, 2010. Archived from the original on March 15, 2012. Retrieved 2015-08-18. 
  3. "Winners : Gladys Knight". Grammy.com. Retrieved 2015-08-18.