Àdàkọ:Chembox KEGG

Glutamic acid (àgékúrú sí Glu tàbí E; tí ó ń kóòdù fún GAA or GAG) jẹ́ α-amino tí wọ́n ń lò lati ṣèdá àwọn protein nínú ara.  Ó ní  α-amino lẹ́gbẹ́ kan (èyí tí ó ní agbára −NH3+ lábẹ́ ààyé), àti α-carboxylic acid lẹ́gbẹ́ kan (èyí tí kò ní agbára −COO lábẹ́ ààyé), àti carboxylic acid tí ó somọ́ lẹ̀gbẹ́, tí a sì kó wọn pọ́ sí àwọn tí kò lágbára lati túká sómi (ní pH ara), aliphatic amino acid. Kò ṣe pàtàkì lára ènìyàn nítorí ara lè ṣẹ̀dá rẹ̀. Ní ìmọ̀ àrùn ọpọlọ,  carboxylate anion ti glutamate jẹ́ ohun tí ó máa ń fún  neurotransmitter lágbára lati ṣisẹ́ ìtají àwọn ètò ọpọlọ.[4] Base tó ní hydrogen ion jẹ́ glutamate; tí radical rẹ̀ jẹ́ sì glutamyl.

Glutamic acid
{{{Alt}}}
{{{Alt}}}
{{{Alt}}}
Àwọn orúkọ mìíràn 2-Aminoglutaric acid
Identifiers
CAS number 56-86-0 (L isomer)
ChEBI CHEBI:18237
SMILES
InChI
InChI key WHUUTDBJXJRKMK-UHFFFAOYAD
ChemSpider ID 591
Properties
Fọ́múlà mólékùlù C5H9NO4
Ìkójọ mọ́lù 147.13 g mol−1
Appearance white crystalline powder
Density 1.4601 (20 °C)
Ojúàmì ìyọ́

199 °C, 472 K, 390 °F

Solubility in water 7.5 g/L (20 °C)[1]
Solubility 0.00035g/100g ethanol
(25 °C)[2]
Acidity (pKa) 2.10, 4.07, 9.47 [3]
Hazards
NFPA 704
1
2
0
 Àdàkọ:Cross(what is this?)  (verify)
Except where noted otherwise, data are given for materials in their standard state (at 25 °C, 100 kPa)
Infobox references

Ẹ̀kọ́ ẹ̀lá

àtúnṣe

ìsomọ́ ẹlẹ́gbẹ́ fún iṣẹ́ ṣiṣe carboxylic acid ní pKa tí ó jẹ́ 4.1.

Ìṣẹ̀dá

àtúnṣe
Reactants Products Enzymes
Glutamine + H2O Glu + NH3 GLS, GLS2
NAcGlu + H2O Glu + Acetate N-acetyl-glutamate synthase
α-ketoglutarate + NADPH + NH4+ Glu + NADP+ + H2O GLUD1, GLUD2[5]
α-ketoglutarate + α-amino acid Glu + α-keto acid transaminase
1-Pyrroline-5-carboxylate + NAD+ + H2O Glu + NADH ALDH4A1
N-formimino-L-glutamate + FH4 Glu + 5-formimino-FH4 FTCD
NAAG Glu + NAA GCPII

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2016-09-11. Retrieved 2016-07-02. 
  2. Belitz, H.-D; Grosch, Werner; Schieberle, Peter (2009-02-27). Food Chemistry. ISBN 9783540699330. https://books.google.com/?id=xteiARU46SQC&pg=PA15. 
  3. http://www.cem.msu.edu/~cem252/sp97/ch24/ch24aa.html
  4. Robert Sapolsky (2005). "Biology and Human Behavior: The Neurological Origins of Individuality, 2nd edition". The Teaching Company. "see pages 19 and 20 of Guide Book"