Ile-iwe Greensprings jẹ ile-iwe British kan ni Nigeria. A da kalè ni Odun 1985 ni ìpínlè Eko . Ile-iwe naa ní aye fún àwon omo Crèche, nosiri, alakobere ati Sekondiri. Ilé-ìwé náà ni ogba méta, ogba Anthony, Lekki-eti-osa àti Ikoyi.

Ile-iwe naa bẹrẹ bi ile-iwe montessori ni Oṣu Kini ọdun 1985, pẹlu awọn ọmọ ile-iwe mẹta (3), ni aarin ilu Èkó. Lówólówó ile-iwe náà ní ogbà méta otooto ni Ilu Eko, pẹlu awọn ọmọ ile-iwe ti o ju 3,500 lo. [1]

Akojọ awọn olori ile-iwe (Lekki Campus)

àtúnṣe
  • 2005 – 2007: Mr. Howard Bullock
  • 2008 – 2010: Mrs. Maeve Stevenson
  • 2010 – 2016: Mrs. Harry McFaul
  • Ọdun 2016 – 2019: Mr. Bola Kolade
  • 2019 – lọwọlọwọ: Mrs. Feyisara Ojugo

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. "Abdullahi commends Greensprings Schools". Vanguard News. March 4, 2013. Retrieved September 20, 2022.