Gwendolyn Brooks
Gwendolyn Elizabeth Brooks (June 7, 1917 – December 3, 2000) je olukowe omo orile-ede Amerika. Won yan bi Poet Laureate Consultant in Poetry to the Library of Congress in 1985.[1]
Gwendolyn Brooks | |
---|---|
Iṣẹ́ | Poet |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United States of America |
Ìgbà | 1930-2000 |
Genre | Poetry |
Notable works | Annie Allen |
Notable awards | Pulitzer Prize for Poetry (1950) |
Spouse | Henry Blakely (m. 1939) |
Igbesiaye
àtúnṣeIgba ewe
àtúnṣeGwendolyn Elizabeth Brooks je bibi ni June 7, 1917, ni Topeka, Kansas fun David Anderson Brooks ati Keziah Wims, o je akobi. Iya re je oluko tele ki o to fi se sile lati setoju awon omo re, baba re, to je omo eru to ja ninu Ogun Abele, je asona nitoripe ko ni owo lati losi ile-eko onisegun lati di dokita. Nigbati Brooks di omo ose mefa, won ko lo si Chicago, Illinois, nibi to ti dagba.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Poet Laureate Timeline: 1981-1990". Library of Congress. 2008. Retrieved 2008-12-19.