Hakeem Babatunde Fawehinmi (ọjọ́ìbí 29 Kẹsán 1969) jẹ Òjògbón ọmọ Nàìjíríà tí Clinical Anatomy atí Biomedical Anthropology atí Ìgbákejì Chancellor tí Nigerian British University.[1][2]

Hakeem Babatunde Fawehinmi
Ìgbákejì Chancellor tí Nigerian British University
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2023
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Hakeem Babatunde Fawehinmi

29 Oṣù Kẹ̀sán 1969 (1969-09-29) (ọmọ ọdún 55)
Ìpínlẹ̀ Òndó
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́Hadeezat Omotayo Fawehinmi

Ibéré ayé atí lẹhìn

àtúnṣe

Fawehinmi gba oyè tí Anatomy atí MBBS láti University of Port Harcourt. Ọ gba Master of Medical Anthropology láti Ilé-ẹ̀kọ́ giga tí Ìlú Lọndọnu atí Dókítà tí Òògùn laπti Ilé-ẹ̀kọ́ University of Port Harcourt.[3]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Hakeem Fawehinmi bẹ̀rẹ bí òṣìṣẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ iṣoogun ní University of Port Harcourt Teaching Hospital ní 1992. Láti ibẹ̀ ọ tí gbaṣẹ́ gẹ́gẹ́bí Lecturer II ní 1995 nípasẹ ilé-ẹ̀kọ́ gígá kànnà ọ sí dìdé sí ipò òjògbón ní May 2010.[4][5]

Fawehinmi ṣé olórí Department of Anatomy, UNIPORT láti odún 2005 sí 2007. Ọ tún ṣiṣẹ́ bí Associate Dean atí Dean, Olùkọ tí Faculty of Basic Medical Sciences, College of Health Sciences, University of Port Harcourt láti 2012 sí 2014.[6]

Ọ jẹ Ìgbákejì Alàkóso fún University of Port Harcourt láti 2016-2020.[7] Ọ tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bí Akòwé Gbogbogbò atí ọmọ ẹgbẹ́ tí Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ tí Orílẹ-èdè tí Ẹgbẹ́ Iṣoogun tí Nàìjíríà, Abala Ìpínlẹ̀ Rivers láti 1999 sí 2000.[8]

Ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù Kínní, ọdún 2023, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Ìgbákejì Nigerian British University nípasẹ Pro-Chancellor atí Alága tí Ìgbimọ Alàkóso tí Ilé-ẹ̀kọ́ Nigerian British University, Ọ́gbẹ́ni Chukwuemeka Umeoji.[9][10]

Àwọn ìtọkásí

àtúnṣe
  1. Olokor, Friday (2023-02-27). "UNIPORT don appointed varsity VC". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-20. 
  2. "Vice Chancellor - Nigerian British University". nbu.edu.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-05-16. Retrieved 2023-05-20. 
  3. "Hakeem FAWEHINMI". Hakeem FAWEHINMI (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-20. 
  4. admin (2023-02-24). "Nigerian British Varsity appoints Prof Hakeem Fawehinmi pioneer VC". National Update (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-05-20. Retrieved 2023-05-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Vice Chancellor - Nigerian British University". nbu.edu.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-05-16. Retrieved 2023-05-20. 
  6. "University of Port Harcourt – Faculty of Basic Medical Science". basicmedicalsciences.uniport.edu.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-05-01. 
  7. "University of Port Harcourt – Faculty of Pharmaceutical Sciences". pharmaceuticalsciences.uniport.edu.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-20. 
  8. Olokor, Friday (2023-02-27). "UNIPORT don appointed varsity VC". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-24. 
  9. Rapheal (2023-03-01). "Fawehinmi appointed Nigerian British varsity VC". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-20. 
  10. "Vice Chancellor - Nigerian British University". nbu.edu.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-05-16. Retrieved 2023-05-20.