Har Gobind Khorana, tabi Hargobind Khorana (Pùnjábì: ਹਰਿ ਗੋਬਿੰਦ ਖੁਰਾਨਾ, January 9, 1922 - November 9, 2011[2]) je omo abinibi India ara Amerika to je aseogunalemin (biochemist) to pin Ebun Nobel fun Iwosan odun 1968 pelu Marshall W. Nirenberg ati Robert W. Holley fun iwadi to fihan bawo ni awon nukleotidi inu ikan nukleiki, ti won ungbe amioro alabimo ahamo, se un kojanu idaropo awon protein.

Har Gobind Khorana
Har Gobind Khorana
Ìbí(1922-01-09)Oṣù Kínní 9, 1922
Raipur, Punjab, British India (now Pakistan)
AláìsíNovember 9, 2011(2011-11-09) (ọmọ ọdún 89)
Concord, Massachusetts
IbùgbéUSA
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican[1]
PápáMolecular Biology
Ilé-ẹ̀kọ́MIT (1970 - )
University of Wisconsin, Madison (1960-70)
University of British Columbia (1952-60)
Cambridge University (1950-52)
Swiss Federal Institute of Technology, Zurich (1948-49)
Ibi ẹ̀kọ́University of Liverpool (Ph.D.)
University of the Punjab (B.S.)(M.S.)
Ó gbajúmọ̀ fúnFirst to demonstrate the role of Nucleotides in protein synthesis
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Medicine (1968)
Religious stanceHinduism