Hassan Usman Sokodabo je olóṣèlú ọmọ Nàìjíríà . O jẹ ọmọ ẹgbẹ ti o nsoju Abaji / Gwagwalada / Kuje / Kwali ni Ile ìgbìmò aṣòfin. [1] [2]

Hassan Usman Sokodabo
Member of the
House of Representatives of Nigeria
from Federal Capital Territory
ConstituencyAbaji/Gwagwalada/Kuje/Kwali
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1969
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeoples Democratic Party
OccupationPolitician

Igbesi aye ibẹrẹ

àtúnṣe

Ọdún 1969 ni wón bi Hassan Usman Sokodabo [1] [2]

Ìrìnàjò òṣèlú

àtúnṣe

Ni ọdun 2022 ó dije dùn ipò nínú ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) nínú ìdíje àlábenu títí ẹgbẹ ti òsì tẹ síwájú gẹgẹbi oludije tí ẹgbẹ fà kalẹ nínú ètò ìdìbò Gbogbogbòò ni ọdun 2023 tí osi ja èwe olubori gẹgẹbi aṣofin àgbà fún ìgbà kejì. Sokodabo to fi ìgbà kan jẹ Komisona olú ìlú Abuja ni Federal Character Commission. Pẹlu àjọṣe pò àwọn aṣofin ọtí ṣe atokun àbá do fín márùn-ún.[3][4]

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 https://constrack.ng/legislator_details?id=359 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name ":0" defined multiple times with different content
  2. 2.0 2.1 https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/hassan-sokodabo-usman Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name ":1" defined multiple times with different content
  3. https://dailyasset.ng/sokodabo-wins-pdp-abuja-south-house-of-representatives-ticket/
  4. https://orderpaper.ng/new/?p=2961