Hattie McDaniel

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Hattie McDaniel (10, osù ke̩fà, o̩dún 1895 – 25, osù ke̩wà, o̩dún 1952) je óṣèrè lobinrin omo Afrika Amerika akoko to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Hattie McDaniel
Hattie McDaniel ni 1941
Ọjọ́ìbí(1895-06-10)Oṣù Kẹfà 10, 1895
Wichita, Kansas, U.S.
AláìsíOctober 26, 1952(1952-10-26) (ọmọ ọdún 57)
Woodland Hills, California, U.S.
Iṣẹ́Osere
Ìgbà iṣẹ́1932–1949
Olólùfẹ́Larry Williams (1949-1950) (divorced)
James Lloyd Crawford (1941-1945) (divorced)
Howard Hickman (1938-1938) (divorced)
George Langford (1922-1922) (his death)

Ìgbèsi Àyé Àràbinrin naa

àtúnṣe

McDaniel jẹ ọmọ to kèrèju ninu awọn ọmọ mẹtala ti awọn óbi rẹ bi. Óṣèrè lóbinrin naa ni à bi ni ọdun 1893 fun awọn ti akó lèru Susan Holbert (Ólórin ti gospel) ati Henry McDaniel ni Winchita, Kansas[2].

McDaniel fẹ Howard Hickman ni óṣu January 19 ni ọdun 1911 ni Denver, Colorado. Howard ku ni ọdun 1915. Ọkọ óṣèrè lóbinrin keji George Langford ku lori egbo ibọn ni óṣu kíní ọdun 1925 ni kó pẹ ti wọn fẹ ara wọn. Hattie fẹ James Lloyd Crawford ni 21 óṣu ke̩ta, ọdun 1941 ti wọn si pinya ni ọdun 1945 lẹyin igbeyawó ọdun mẹrin abọ[3]. Hattie fẹ Larry Williams ni 11 óṣu ke̩fà, ni ọdun 1949 ni Yuma, Arizona ti wọn si pinya ni ọdun 1950[4].

Ni àsiko Ogun Agbaye kèji, Hattie jẹ oludari e̩gbé̩ ti Negro Abala ti Hollywood Victory ti óun ṣẹyẹ fun awọn ologun ti wọn wa ni àwọn ìpìlẹ̀ ológun[5]. Óṣèrè lóbinrin naa darapọ mọ óṣèrè Clarence Muse ti ó jẹ ọkan lara awọn ọmọ ẹgbẹ Alawọ dudu ti óṣèrè Screen Guild lati da ówò fun Red Cross fun awọn ọmọ ilẹ amerika ti ómi yalè àgbàrà ya ṣobu kọlu.

Ikú rẹ̀

àtúnṣe

McDaniel ku lori aisan jẹjẹrẹ ọmu ni ọmọ ọdun 59 ni 26 óṣu ke̩wà ni ọdun 1952 ni ilè iwosan ti lé awòrán ìs̩ípòpadà ni Woodland Hills, California[6][7].

Hattie lọsi ilè iwè ti Denver East lati 1908 de 1910[8].

Ipa Òṣèrè lóbinrin ninu èré àgbèlèwó

àtúnṣe

Features

Ọdun Akọlè Ipa Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwò Akiyèsi
1932 Love Bound
1932 Impatient Maiden Injured Patient uncredited
1932 Are You Listening? Aunt Fatima - Singer uncredited
1932 The Washington Masquerade Maid uncredited
1932 The Boiling Point Caroline the Cook uncredited
1932 Crooner Maid in Ladies' Room uncredited
1932 Blonde Venus Cora, Helen's Maid in New Orleans uncredited
1932 The Golden West Mammy Lou uncredited
1932 Hypnotized Powder Room Attendant uncredited
1933 Hello, Sister Woman in Apartment House uncredited
1933 I'm No Angel Tira's Maid-Manicurist uncredited
1933 Goodbye Love Edna the Maid uncredited
1934 Merry Wives of Reno Bunny's Maid uncredited
1934 City Park Tessie - the Ransome Maid uncredited
1934 Operator 13 Annie uncredited
1934 King Kelly of the U.S.A. Black Narcissus Mop Buyer uncredited
1934 Judge Priest Aunt Dilsey
1934 Imitation of Life Woman at Funeral uncredited
1934 Flirtation Minor Role uncredited
1934 Lost in the Stratosphere Ida Johnson
1934 Babbitt Rosalie, the Maid uncredited
1934 Little Men Asia uncredited
1935 The Little Colonel Mom Beck
1935 Transient Lady Servant uncredited
1935 Traveling Saleslady Martha Smith uncredited
1935 China Seas Isabel McCarthy, Dolly's Maid uncredited
1935 Alice Adams Malena Burns
1935 Harmony Lane Liza, the Cook uncredited
1935 Murder by Television Isabella - the Cook
1935 Music Is Magic Hattie
1935 Another Face Nellie - Sheila's Maid uncredited
1935 We're Only Human Molly, Martin's Maid uncredited
1936 Next Time We Love Hanna uncredited
1936 The First Baby Dora
1936 The Singing Kid Maid uncredited
1936 Gentle Julia Kitty Silvers
1936 Show Boat Queenie
1936 High Tension Hattie
1936 The Bride Walks Out Mamie - Carolyn's Maid
1936 Postal Inspector Deborah uncredited
1936 Star for a Night Hattie
1936 Valiant Is the Word for Carrie Ellen Belle
1936 Libeled Lady Maid in Grand Plaza Hall uncredited
1936 Can This Be Dixie? Lizzie
1936 Reunion Sadie
1937 Racing Lady Abby
1937 Don't Tell the Wife Mamie, Nancy's Maid uncredited
1937 The Crime Nobody Saw Ambrosia
1937 The Wildcatter Pearl uncredited
1937 Saratoga Rosetta
1937 Stella Dallas Maid
1937 Sky Racket Jenny
1937 Over the Goal Hannah
1937 Merry Go Round of 1938 Maid uncredited
1937 Nothing Sacred Mrs. Walker uncredited
1937 45 Fathers Beulah
1937 Quick Money Hattie uncredited
1937 True Confession Ella
1937 Mississippi Moods
1938 Battle of Broadway Agatha
1938 Vivacious Lady Hattie - Maid at Prom Dance uncredited
1938 The Shopworn Angel Martha
1938 Carefree Hattie uncredited
1938 The Mad Miss Manton Hilda
1938 The Shining Hour Belvedere
1939 Everybody's Baby Hattie
1939 Zenobia Dehlia
1939 Gone with the Wind Mammy - House Servant
1940 Maryland Aunt Carrie
1941 The Great Lie Violet
1941 Affectionately Yours Cynthia
1941 They Died with Their Boots On Callie
1942 The Male Animal Cleota
1942 In This Our Life Minerva Clay
1942 George Washington Slept Here Hester, the Fullers' Maid
1943 Johnny Come Lately Aida
1943 Thank Your Lucky Stars Gossip in 'Ice Cold Katie' Number
1944 Since You Went Away Fidelia
1944 Janie April - Conway's Maid
1944 Three Is a Family Maid
1944 Hi, Beautiful Millie
1946 Janie Gets Married April
1946 Margie Cynthia
1946 Never Say Goodbye Cozie
1946 Song of the South Aunt Tempy
1947 The Flame Celia
1948 Mickey Bertha
1948 Family Honeymoon Phyllis
1949 The Big Wheel Minnie

Short films

Ọdun Àkọlè Ipa Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwó Àkiyèsi
1934 Mickey's Rescue Maid uncredited
1934 Fate's Fathead Mandy - the Maid uncredited
1934 The Chases of Pimple Street Hattie, Gertrude's Maid uncredited
1935 Anniversary Trouble Mandy, the Maid Our Gang
1935 Okay Toots! Hattie - the Maid uncredited
1935 Wig-Wag Cook uncredited
1935 The Four Star Boarder Maid uncredited
1936 Arbor Day Buckwheat's Mother Our Gang
1938 Termites of 1938 Three Stooges
Ọdun Program Episode/source
1941 Gulf Screen Guild Theatre No Time for Comedy

Àmi Ẹyẹ ati Idànilọla

àtúnṣe

Hattie jẹ óṣèrè lóbinrin ilẹ Afirika ati Amerika to mà gbà amin ẹyẹ Oscar[9]. Óṣèrè lóbinrin naa gbà irawọ meji lori Hollywood walk of fame ti wọn si gba wọlè si Awọn Alawọ dudu ti wọn jẹ óṣere Hall of Fame ni ọdun 1975. Hattie jẹ akọkọ Ẹni tó gba Oscar ti wọn fun Postage Stage ti ilẹ U.S gẹgẹbi àmi idàlọla to waye ni ọdun 2006[10]. Ni ọdun 2010 ni wọn gba óṣèrè lóbinrin wọlè si Colorado Hall ti Fame ti awọn obinrin[11].