Heart of Men
Heart of Men (tí wọ́n yípadà ní Nollywood sí Forbidden Fruit láti ọwọ́ Henrikesim Multimedia Concept for International distribution) jẹ́ fíìmú ti orílẹ̀-èdè Ghana tí ó jáde ní ọdún 2009. Frank Rajah Arase ni olùdarí àti aṣàgbéjáde fíìmù yìí, lára àwọn òṣèré tó kópa nínú rẹ̀ ni Majid Michel, John Dumelo, Prince David Osei àti Yvonne Nelson. Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ márùn-ún ní Africa Movie Academy Awards ẹlẹ́ẹ̀kẹfà.
Heart of Men | |
---|---|
Fáìlì:Heart of Men CD poster.jpg Ghanaian release poster | |
Adarí | Frank Rajah Arase |
Olùgbékalẹ̀ | Frank Rajah Arase |
Àwọn òṣèré |
|
Orin | Okyeama Qouphi |
Ìyàwòrán sinimá | Adam Umar |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Heroes Films Raj Films Henrikesim Multimedia Concept |
Olùpín | Henrikesim Multimedia Concept |
Orílẹ̀-èdè | Ghana Nigeria |
Èdè | English |
Àwọn òṣèré tó kópa
àtúnṣe- Majid Michel bí i Richie
- John Dumelo bí i Kay
- Prince David Osei bí i Ray
- Yvonne Nelson bí i Tracy
- Martha Ankomah bí i Diana
- Kofi Adjorlolo bí i Bernard
- Gavivina Tamakloe bí i Ọlọ́pàá
- Nadia Buari bí i Sylvia
- Luckie Lawson bí i Alicie
- Jackie Appiah bí i Whitney
- Jackie Appiah bí i Adline
Ìgbàwọlé
àtúnṣeWọ́n bu ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹnu àtẹ́ lu fíìmù yìí nítorí bí wọ́n ṣe ṣe ìgbélárugẹ ìmúra-ìhòhò àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáraẹnilòpọ̀ tó hàn nínú fíìmù yìí.[1][2][3] Ó gba àmì mẹ́ta nínú márùn-ún ní orí Nollywood Reinvented tí ó gbóríyìn fún àgbéjáde fíìmù yìí pẹ̀lú iṣẹ́ tó dára, orin tó dára, ibùdó ìtàn tó yàtọ̀, àmọ́ ó ní àhunpọ̀ ìtàn inú rẹ̀ ti kẹnú jù, àti pé àwọn ìfarahàn ìbálòpọ̀ nínu fíìmù náà ti pọ̀ jù.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Heart of Men: Soft Porn?". Ghana Nation. Archived from the original on 14 April 2014. Retrieved 13 April 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "From Ghana with Soft Porn". Nigeriafilms.com. Archived from the original on 16 April 2014. Retrieved 13 April 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Frank Rajah regrets introducing Nudity to Ghollywood". Retrieved 13 April 2014.
- ↑ "Heart of Men Review on NR". Retrieved 13 April 2014.