Kofi Adjorlolo
Kofi Adjorlolo (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta ọdún 1956 ní ìlú Keta) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana.
Kofi Adjorlolo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 June 1956 Keta– Volta region Ghana |
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Keta Senior High Technical School |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1980–present |
Awards | International Golden Image award |
Wọ́n ti yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ̀ òṣèrékùnrin tó dára jù rí ní Ghana Movie Awards, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n ti yàn án nígbà mẹ́rin tí fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrẹ́kùnrin tó dára jù ní, Ghana Movie Awards, Africa Movie Academy Awards, àti ní Africa Magic Viewers Choice Awards. Lára àwọn àmì-ẹ̀yẹ mìíràn tó ti gbà ni International Golden Image award láti ọwọ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Liberia nígbà kan rí, ìyẹn Ààrẹ Ellen Johnson Sirleaf,[1] àti àmì-ẹ̀yẹ Best Cameo Actor ní 2011 Ghana Movie Awards.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Kofi Adjorlolo sí ìlú Keta, ní agbègbè Volta, ní Ghana. Láti ìgbà èwe rẹ̀ ni ó ti nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́-ọnà, pàápàá jù lọ orin, àmọ́ iṣẹ́ eré ṣíṣe ló padà ṣe nígbà tí ó dàgbà. Adjorlolo tẹ̀síwájú nínú ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Ghana, ó lọ sí Keta Senior High Technical School, níbi tí àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní farahàn, látàri àwọn ìkópa rẹ̀ nínú àwọn ayẹyẹ ilé-ìwé náà. [2][3]
Àṣàyàn àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeYear | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2003 | The Chosen One Part 1&2 | Deacon Prempeh | |
2006 | My Mother's Heart | Boakye | Nominated for Best Actor (Supporting Role) at the 2nd Africa Movie Academy Awards |
2007 | Princess Tyra | King | |
2009 | Heart of Men | Bernard | |
2009 | Agony of Christ | ||
2010 | The Beast | Dr. Brooks | Nominated for Best Actor in a Supporting Role (English) at the 2010 Ghana Movie Awards |
2011 | Ties that Bind | Father | |
2011 | Somewhere in Africa | General Olemba | Winner, Best Cameo Actor at the 2011 Ghana Movie Awards |
2012 | Adesuwa (A Wasted Lust) | ||
2012 | Single and Married | Ranesh | |
2012 | Wipe My Tears | Nominated for Best Actor in a Lead Role (English) at the 2012 Ghana Movie Awards | |
2014 | Family Album | Nominated for Best Actor in a Supporting Role at the 2014 Ghana Movie Awards | |
2014 | A Northern Affair | ||
2015 | Code of Silence | ||
2015 | Falling | Mr Mazi Mba | |
2016 | Ghana Must Go | father | Nominated for Best Supporting Actor Movie/TV series at the 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards |
2017 | Crime Suspect | ||
2018 | That Night | ||
2019 | Hero: Inspired by the Extraordinary Life and Times of Mr. Ulric Cross[4] | Asantehene | |
2020 | Aloe Vera[5][6] | Papa Aloe |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Kofi Adjorlolo, Osu Mantse honoured in Liberia". Ghana Web. 24 July 2017. Archived from the original on 24 April 2019. https://web.archive.org/web/20190424083626/https://www.ghanaweb.com/GhanaHomePage/NewsArchive/Kofi-Adjorlolo-Osu-Mantse-honoured-in-Liberia-562055. Retrieved 24 November 2018.
- ↑ "Kofi Adjorlolo's Early Life and Career Journey". GhanaWeb. 2019.
- ↑ "A Look at Kofi Adjorlolo’s Formative Years". MyJoyOnline.com. 2020.
- ↑ Solomon, Frances-Anne (22 June 2019), HERO Inspired by the Extraordinary Life & Times of Mr. Ulric Cross (Drama), Kofi Adjorlolo, Jimmy Akingbola, Giles Alderson, Tessa Alexander, HeroFilm, HeroFilm, CaribbeanTales, retrieved 2021-02-03
- ↑ Sedufia, Peter (6 March 2020), Aloevera (Drama, Romance), Benjamin Adaletey, Aaron Adatsi, Ngozi Viola Adikwu, Kofi Adjorlolo, OldFilm Productions, retrieved 2021-02-03
- ↑ "Film review: Aloe Vera offers some charm in its vibrant retort to irrational tribalism". Citinewsroom – Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 March 2020. Retrieved 2021-02-03.