Heineken Lokpobiri
Olóṣèlú
Heineken Lokpobiri jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]
Heineken Lokpobiri | |
---|---|
Aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù kẹrin Ọdún 2007 | |
Constituency | Ìwọ̀ oòrùn Bayelsa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹta Ọdún 1967 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Occupation | Amòfin àti Olóṣèlú |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Senate passes Elderly Persons Bill". TIMBUKTU MEDIA. July 15, 2009. Retrieved 2009-09-17.
- ↑ Hope Abah (11 April 2011). "SSS arrest Sen. Lokpobiri in Yenagoa". Daily Trust. Archived from the original on 2012-06-30. Retrieved 2012-05-25.
- ↑ Bunmi Awolusi (April 28, 2011). "Court restrains INEC from conducting rescheduled Bayelsa polls – Channels". Channels TV. Archived from the original on 2011-04-30. Retrieved 2011-06-18.