Henri-Joseph Koumba Bididi

Henri-Joseph Koumba Bididi ( Èdè Lárúbáwá: هنري جوزيف كومبا بيديدي; tí wọ́n bí ní 15 Oṣù Keèje, Ọdún 1957) jẹ́ ònkọ̀tàn àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Gabon tí ó maá n sábà ṣiṣẹ́ lóri àwọn eré ìrírí.[1] Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìrírí tó fi mọ́ The King's Necklace àti Le Singe Fou.[2][3]

Henri-Joseph Koumba Bididi
هنري جوزيف كومبا بيديدي
Ọjọ́ìbíHenri-Joseph Koumba Bididi
15 Oṣù Keje 1957 (1957-07-15) (ọmọ ọdún 67)
Omboué, Gabon
Orílẹ̀-èdèGabonese
Iléẹ̀kọ́ gígaÉcole supérieure d'études cinématographiques
Iṣẹ́Director, producer, screen writer
Ìgbà iṣẹ́1983–present

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Henri Joseph Koumba Bididi: Director, Screenwriter". unifrance. Retrieved 8 October 2020. 
  2. "Henri-Joseph Koumba Bididi career". Afri Cultures. Retrieved 8 October 2020. 
  3. "Henri Joseph Koumba Bididi: Director, Producer". MUBI. Retrieved 8 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe