Gàbọ̀n (play /ɡəˈbɒn/; pípè ní Faransé: [ɡabɔ̃]), lonibise bi Orile-ede Olominira ara Gabon (Faranse: [République Gabonaise] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) je orile-ede ni iwoorun gbongan Afrika to ni bode mo Guinea Alagedemeji ni ariwaiwoorun, Cameroon ni ariwa, ati mo Orile-ede Olominira ile Kongo to lopo ni ilaorun ati guusu. Ikun-omi Guinea, apa Okun Atlantiki si iwoorun. Ile re tobi to 270,000 km² o si ni alabugbe to to 1,500,000. Oluilu ati ilu totobijulo re ni Libreville.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Gàbọ̀n
Gabonese Republic
République Gabonaise
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Union, Travail, Justice"
(Faransé fún "Ìṣọ̀kan, Iṣẹ́, Ìdájọ́")
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèLa Concorde
The Concord
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Libreville
0°23′N 9°27′E / 0.383°N 9.45°E / 0.383; 9.45
Èdè àlòṣiṣẹ́ French
Vernacular languages Fang, Myene
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2000) Fang 28.6%
Punu 10.2%
Nzebi 8.9%
French 6.7%
Mpongwe 4.1%
other Africans
and Europeans 154,000
(including 10,700 French and 11,000 persons of dual nationality)
Orúkọ aráàlú Ará Gàbọ̀n
Ìjọba Orílẹ̀-èdè olómìnira oníààrẹ
 -  Ààrẹ Ali Bongo Ondimba
 -  Alákóso Àgbà Raymond Ndong Sima
Aṣòfin Iléaṣòfin
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà Ilé Alàgbà
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Independence
 -  from France August 17, 1960 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 267,667 km2 (76th)
103,347 sq mi 
 -  Omi (%) 3.76%
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 1,475,000[1] (150th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 5.5/km2 (216th)
14.3/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2011
 -  Iye lápapọ̀ $24.571 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $16,183[2] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2011
 -  Àpapọ̀ iye $16.176 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $10,653[2] 
HDI (2010) 0.648[3] (medium) (93rd)
Owóníná Central African CFA franc (XAF)
Àkókò ilẹ̀àmùrè WAT (UTC+1)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+1)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ga
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 241

Lati igba ilominira latowo Fransi ni August 17, 1960, awon aare meta loti joba ni Gabon. Ni arin ewadun 1990, Gabon bere sistemu egbe oloselu pupo ati isepo oloselu tuntun to fi aye gba igbese aladiboyan kedere to si satunse opo awon ise ijoba. Gabon ti je omo-egbe alaije tigba gbogbo ni Igbimo Abo UN fun igba 2010-2011.

Low Isupo alabugbe kekere lapapo mo opo awon ohun alumoni ati idawosi aladani okere ti so Gabon di ikan ninu awon orile-ede to jomitoro julo ni Afrika, pelu HDI to gajulo[4] ati GDP ti enikookan togajulo keta (PPP) (leyin Equatorial Guinea ati Botswana) ni agbegbe yi.


ItokasiÀtúnṣe

  1. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Gabon". International Monetary Fund. Retrieved 2012-04-18. 
  3. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
  4. "Human Development Report 2011 - Human development statistical annex" (PDF). HDRO (Human Development Report Office United Nations Development Programme. pp. 127–130. Retrieved 2 November 2011.