Hifikepunye Lucas Pohamba (ojoibi August 18, 1935) je oloselu omo ile Namibia. Lowolowo ohun ni Aare Orile-ede Namibia. Won koko diboyan wole ni 2004, o si tun pade yori ninu idiboyan to waye ni 27 ati 28 November, 2009. Egbe oloselu SWAPO ti Pohamba je olori gba 77.82% ibo.[2]

Hifikepunye Lucas Pohamba
President of Namibia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
21 March 2005
Alákóso ÀgbàNahas Angula
AsíwájúSam Nujoma
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹjọ 1935 (1935-08-18) (ọmọ ọdún 89)
Okanghudi, Namibia
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSWAPO
(Àwọn) olólùfẹ́Penehupifo Pohamba