Nahas Angula
Nahas Gideon Angula (ojoibi 22 August 1943[1][2]) ni Alákóso Àgbà ile Namibia. O gun ori aga ni March 21 2005, Aare Hifikepunye Pohamba lo yansise.[3]
Nahas Gideon Angula | |
---|---|
Alakoso Agba ile Namibia | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 21 March 2005 | |
Ààrẹ | Hifikepunye Pohamba |
Asíwájú | Theo-Ben Gurirab |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kẹjọ 1943 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | SWAPO |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Katrina Tangeni Namalenga |
Àwọn ọmọ | two [1] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Profile on Namibian parliament website.
- ↑ Biographies of Namibian Personalities, klausdierks.com.
- ↑ "Namibia's new president takes office", AFP (IOL), March 22, 2005.