Hiroshima (広島市 Hiroshima-shi?) (ja-Hiroshima.ogg listen ) jẹ́ ìlú ní orílẹ̀ èdè Japan àti olúìlú Ìbílẹ̀ Hiroshima, ó sì tún jẹ́ ìlú tótóbijùlo ní agbègbè Chūgoku ní apáìwọ̀ọ̀rùn Honshū, tó jẹ́ erékùṣù títóbijùlọ ní Japan. Ó jẹ́ ìlú àkọ́kọ́ nínú ìtàn tó jẹ́ piparun pẹ̀lù bọmbù átọ́mù nígbà tí orílẹ̀ èdè Améríkà jù síbẹ̀ ní ago 8:15 am ọjọ kẹfà Oṣù kẹjọ Ọdún 1945, ní súnmọ́ òpin Ogun Àgbáyé Kejì.[1]

Hiroshima
広島
Designated city
広島市 · Hiroshima City
Atomic Bomb Dome (left) and modern buildings
Atomic Bomb Dome (left) and modern buildings
Flag of Hiroshima
Flag
Location of Hiroshima in Hiroshima Prefecture
Location of Hiroshima in Hiroshima Prefecture
Country Japan
Region Chūgoku, Sanyō
Prefecture Hiroshima
Ìjọba
 • Mayor Tadatoshi Akiba (SDP)
Ìtóbi
 • Total 905.01 km2 (349.43 sq mi)
Agbéìlú (January 2010)
 • Total 1,173,980
 • Density 1,297.2/km2 (3,360/sq mi)
Time zone Japan Standard Time (UTC+9)
- Tree Camphor Laurel
- Flower Oleander
Phone number 082-245-2111
Address Hiroshima-shi,
Naka-ku, Kokutaiji 1-6-34
730-8586
Website Hiroshima City

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. Hakim, Joy (1995). A History of Us: War, Peace and all that Jazz. New York: Oxford University Press. ISBN 0-19-509514-6.