Honiara
Honiara, pelu iye eniyan to je 49,107 (1999), 54,600 (idiye 2003), ni oluilu awon Erekusu Solomoni ati fun igberiko Guadalkanal nibe. "Honiara" je oruko ti awon olumusin ara Ilegeesi si pe nitoripe o soro fun won lati pe ibe pelu oruko re gangan to n je Nagoniara. Nagoniara tumosi "niwaju iji."
Honiara | |
---|---|
Main Street, Honiara | |
Country | Solomon Islands |
Province | Honiara Town |
Island | Guadalcanal |
Government | |
• Mayor | Andrew Mua |
Population (2003) | |
• Total | 54,600 |
Time zone | UTC+11 (UTC) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |