Huang Xianfan (13 Oṣù Kọkànlá 1899 - 18 Oṣù Kínní 1982) je ojogbon (Professor) ìtàn omo ile Ṣáínà.

Huang Xianfan
Ọjọ́ìbíGan Jinying(甘錦英/甘锦英)
(1899-11-13)Oṣù Kọkànlá 13, 1899
Fusui, Ṣáínà
AláìsíJanuary 18, 1982(1982-01-18) (ọmọ ọdún 82)
Guilin, Ṣáínà
Cause of deathStroke patients
Resting placeGuangxi Zhuang Autonomous Region martyrs cemetery,the names of the martyrs cemetery inscribed by Deng Xiaoping(广西壮族自治区烈士陵园,园名由邓小平亲笔题写)
Orílẹ̀-èdè Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà
Ọmọ orílẹ̀-èdèOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà
Ẹ̀kọ́Normal Unifasiti ni Beijing(1926-1935), Unifasiti Tokyo(1935-1937)
Iṣẹ́Representatives of the National People's Congress(NPC), Members of the CPPCC National Committee
Ìgbà iṣẹ́1954-1958, 1980-1982
Gbajúmọ̀ fúnAs the father of Zhuang studies(壮学之父), the School's leader of Bagui(八桂学派领袖) and Wu Nu(无奴学派导师)
Ọmọ ìlúQusi village, Qujiu town, Fusui county
Political partyChinese Peasants' and Workers' Democratic Party
Olólùfẹ́Liu Lihua(劉麗華/刘丽华)
Àwọn ọmọGan Jinshan(甘金山), Gan Wenhao(甘文豪),Gan Wenjie(甘文杰)
Parent(s)Gan Xinchang(甘新昌)
Website[3]
Notes
Huang Xianfan 1932

Igbesiaye

àtúnṣe

Wón bí Huang Xianfan ní ìlú Fusui, ìpínlè Guangxi ní ọdun 1899. Huang ló ilé èkó primary and junior secondary ni Qujiu àti Fusui, àti ni Nanning' High School ni Guangxi. Lèyìn rè ó ló sí Normal Yunifasiti ni Beijing (Beijing ni oluilu orile-ede Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà) ni 1926-1935 àti Yunifasiti Tokyo (Tokyo ni oluilu orile-ede Japan) ni Japan ni 1935-1937. Leyin eyi ni o lo di ojogbon ìtàn ni Yunifasiti Guangxi ni Ṣáínà ni 1940-1982. [1]

Ìwé tó kọ

àtúnṣe
  • «Outline of Chinese History».Beiping Culture Society, 1932-1934
  • «Brief Introduction on Tang Dynasty». The Commercial Press,1936
  • «Save Nation Movement of Tai-Xue students in Song Dynasty».The Commercial Press,1936
  • «Brief History of Zhuang nationality».Guangxi Peoples’s Press, 1957
  • «No Slave Society in Chinese History». Guangxi Normal University Press ,1981
  • «Nong Zhi Gao». Guangxi Peoples’s Press,1983
  • «General History of Zhuang Nationality». Guangxi National Press ,1988
  • «the Introduction on Chinese Ancient Books». Guangxi Normal University Press ,2004[2]


  1. www.china.com.cn:2008-12-08 [1]
  2. ma.www.china.com.cn:2009-07-17 [2] Archived 2009-11-01 at the Wayback Machine.