Ibikunle Akitoye
Oba of Lagos

Reign 1925-1928
Coronation 1925
Predecessor Eshugbayi Eleko
Successor Sanusi Olusi
Born 1871
Lagos, Nigeria
Died 1928
Lagos
Religion Christianity

Ibikunle Alfred Akitoye [1] (1871–1928) jẹ́Ọba Èkó láti ọdún 1925 sí ọdún 1928 nígbà ohun tí àwọn òpìtàn kan ń pè ní “Interregnum” nígbà ọdún tí Ọba Eshugbayi Eleko ti igbekun. Ibikunle Akitoye jẹ́ ọba èkó àkọ́kọ́ tí ó kàwé tí ó sì jẹ́ Kristẹni. Ìjọba Akitoye tún ṣe àfihàn àjọṣepọ̀ àwọn Ọba ekó pẹ̀lú àwọn ẹ̀sìn amutorunwa.

Ìgbésí ayé Ìbẹ̀rẹ̀ àti iṣẹ́ òòjọ́

àtúnṣe

Ibikunle Alfred Akitoye, jẹ́ ọmọ ọmọ Ọba Akitoye, wọ́n bi ní èkó lọ́dún 1871, ó sì gbẹ̀kọ́ gboyè ní CMS Grammar School . O ṣe iṣẹ́ olùtọ́jú ìwé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Jámánì kan, lẹ́yìn náà ni ó ṣiṣẹ́ bi

  1. Allister Macmillan (1993). The Red Book of West Africa: Historical and Descriptive, Commercial and Industrial Facts, Figures & Resources. Spectrum Books, 1993. p. 113. ISBN 9789782461735. https://books.google.com/books?id=m7s2AQAAMAAJ&q=akitoye+paymaster. Retrieved 30 July 2017.