Ibrahim Khalid Mustapha


Ibrahim Khalid Mustapha jẹ́ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà tó sì tún ń ṣojú ẹ̀gbẹ́ Sẹnetọ̀ ní ìpínlè Kaduna ní àríwá ní ilé ììgbìmò asòfin kẹwàá . O ṣẹgun alátakò rẹ Sulaiman Abdu Kwari, lẹhin ti wọn dibo ni ìdìbò Gbogbogbòò Naijiria ti Ọdún 2023 . Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ilé ìgbìmọ̀ aṣojú tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Soba lati Ọdún 2007-2015 fun Àpéjọ 6th ati 7th. O je omo ẹgbẹ́ People's Democratic Party (PDP). [2] [3]

Ibrahim Khalid Mustapha
Senator of the Federal Republic of Nigeria from Kaduna State North District
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2023
AsíwájúSuleiman Abdu Kwari
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíKaduna
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party[1]

Idibo akọkọ

àtúnṣe

Mustapha jawe olubori ninú ìdìbò alaabẹrẹ ti PDP pẹlu ibo 257, eyi ti o mu ki o di oludije fun ẹgbẹ oṣelu PDP ninu idibo gbogbogbòò Nàìjíríà lọdun 2023.[4] [5]

  • Kaduna North Senatorial DISTRICT

Awọn itọkasi

àtúnṣe