Idibo ile igbimo asofin ipinle Eko lodun 2015
Idibo ile igbimo asofin ipinle Eko lodun 2015 waye ni ojo kokanla osu kerin odun 2015 lati yan awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko ni Naijiria. Gbogbo ogoji ijoko lo wa fun idibo ni ile igbimo asofin ipinle Eko. APC gba aga mejilelogbon, nigba ti PDP gba aga mejo.
Nigba ti sisi ile igbimo asofin ipinle kejo ti waye, Mudashiru Obasa (APC-Agege I) ni won yan gege bi olori ile igbimo asofin nigba ti Wasiu Sanni (APC-Lagos Island I) ati Agunbiade Sanai (APC-Ikorodu I) di igbakeji olori ile igbimo asofin ati ile igbimo asofin. Olori, lẹsẹsẹ.
Esi
àtúnṣeBadagry I
àtúnṣeOludije egbe APC Layode Olanrewaju lo jawe olubori ninu idibo naa.
Apapa II
àtúnṣeOludije egbe APC Jimoh Olumuyiwa lo jawe olubori ninu idibo naa.
Apapa I
àtúnṣeOludije egbe APC Lawal Mojisola Lasbat lo jawe olubori ninu idibo naa.
Alimosho I
àtúnṣeOludije egbe APC, Adebisi Yusuff lo jawe olubori ninu idibo naa.
Alimosho II
àtúnṣeOmo Egbe APC Oduntan Omotayo ni o Jawe Olubori leyin idibo na
Agege II
àtúnṣeOluyinka Ogundimu to jẹ oludije egbe APC lo jawe olubori ninu idibo naa.
Agege I
àtúnṣeOludije egbe APC Mudashiru Obasa lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikeja I
àtúnṣeOludije egbe APC Folajimi Mohammed lo jawe olubori ninu idibo naa.
Kosofe II
àtúnṣeOludije egbe APC Tunde Braimoh lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikeja II
àtúnṣeOludije egbe APC Adedamola Kasumu lo jawe olubori ninu idibo naa.
Somolu II
àtúnṣeOludije egbe APC, Abiru Rotimi Lateef lo jawe olubori ninu idibo naa.
Badagry II
àtúnṣeOludije egbe APC Setonji David lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Island II
àtúnṣeOludije egbe APC Giwa Sakirudeen lo jawe olubori ninu idibo naa.
Epe I
àtúnṣeOludije egbe APC Tobun Abiodun lo jawe olubori ninu idibo naa.
Epe II
àtúnṣeOludije egbe APC Segun Olulade lo jawe olubori ninu idibo naa.
Eti-Osa I
àtúnṣeAlimi Kazeem Ademọla tó jẹ́ olùdíje nínú ẹgbẹ́ òṣèlú APC ló jáwé olúborí ninu idibo na.
Eti-Osa II
àtúnṣeOludije egbe APC Yisawu Olusegun Gbolahan lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ibeju/Lekki I
àtúnṣeOludije egbe APC Mojeed Fatai lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ibeju/Lekki II
àtúnṣeOludije egbe APC Kazeem Raheem Adewale lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ifako/Ijaye I
àtúnṣeOludije egbe APC Dayo Fafunmi lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ifako/Ijaye II
àtúnṣeOludije egbe APC Makinde Rasheed Lanre lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikorodu I
àtúnṣeOludije egbe APC Agunbiade Sanai lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ikorodu II
àtúnṣeOludije egbe APC, Solaja-Saka Nurudeen lo gba ibo naa.
Kosofe I
àtúnṣeOludije egbe APC Osinowo Sikiru lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Island I
àtúnṣeOludije egbe APC Wasiu Sanni lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Mainland I
àtúnṣeOludije egbe APC Adekanye Oladele lo jawe olubori ninu idibo naa.
Lagos Mainland II
àtúnṣeOludije egbe APC, Ọṣun Moshood lo jawe olubori ninu idibo naa.
Mushin I
àtúnṣeOludije egbe APC Tejuoso Funmilayo lo jawe olubori ninu idibo naa.
Mushin II
àtúnṣeOludije egbe APC, Olayiwola Olawale lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ojo II
àtúnṣeOludije egbe APC Lanre Ogunyemi lo jawe olubori ninu idibo naa.
Somolu I
àtúnṣeOludije egbe APC, Rotimi Olowo lo jawe olubori ninu idibo naa.
Surulere I
àtúnṣeOludije egbe APC Desmond Elliot jawe olubori ninu idibo naa.
Surulere II
àtúnṣeOludije egbe PDP Mosunmola Sangodara-Rotimi lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ajeromi/Ifelodun II
àtúnṣeOludije egbe PDP Oluwa Olatunji Fatai lo jawe olubori ninu idibo naa.
Ojo I
àtúnṣeOludije egbe PDP Olusegun Victor Akande lo jawe olubori ninu idibo naa.
Oshodi/Isolo II
àtúnṣeEmeka Odimogu to jẹ oludije ninu egbe PDP lo jawe olubori ninu idibo naa.
Oshodi/Isolo II
àtúnṣeOludije egbe PDP Shokunle Hakeem lo jawe olubori ninu idibo naa.
Amuwo/Odofin II
àtúnṣeOludije egbe PDP Hakeem Bello lo jawe olubori ninu idibo naa.
Amuwo/Odofin I
àtúnṣeOludije egbe PDP Dipo Olorunrinu lo gba ibo naa.
Oludije egbe PDP Famakinwa Adedayo Olufemi lo jawe olubori ninu idibo naa.