Ife North je ọkàn nínú àwọn ìjọba ibile ín agbegbe Osun State, ní orílè èdè Nigeria. Olú ilé rẹ wà ní ilu Ipetumodu ni ariwa tó wà ní 7°31′00″N 4°27′00″E / 7.51667°N 4.45000°E / 7.51667; 4.45000.