Ignacio Milam Tang (ọjọ́ìbí 20 June 1940[1]) ni olóṣèlú ará Gínì Ibialágedeméjì tó jẹ́ Alákóso Àgbà ilẹ̀ Gínì Ibialagedeméjì láti osù keje ọdún 2008 di osù karùún ọdún 2012. Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú Democratic Party of Equatorial Guinea (PDGE).[2] Láti osù karùún ọdún 2012 di osù kẹfà ọdún 2016, ó jẹ́ Igbákejì Ààrẹ Èkínní ilẹ̀ Gínì Ibialágedeméjì, ó jọ wà nípò yí pẹ̀lú ọmọ ọkùnrin Ààrẹ Obiang's, Teodorín.

Ignacio Milam Tang
Ignacio Milam Tang
First Vice President of Equatorial Guinea
In office
21 May 2012 – 22 June 2016
ÀàrẹTeodoro Obiang Nguema Mbasogo
Alákóso ÀgbàVicente Ehate Tomi
AsíwájúOffice established
Arọ́pòTeodorin Obiang
Prime Minister of Equatorial Guinea
In office
8 July 2008 – 21 May 2012
ÀàrẹTeodoro Obiang Nguema Mbasogo
AsíwájúRicardo Mangue Obama Nfubea
Arọ́pòVicente Ehate Tomi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Kẹfà 1940 (1940-06-20) (ọmọ ọdún 84)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDGE