Teodoro Obiang Nguema Mbasogo
Teodoro Obiang Nguema Mbasogo (Pípè: [te.o.ˈðo.ɾo o.ˈβjãŋɡ ˈŋ.ɡe.ma m.ˈba.so.go]; ọjọ́ìbí 5 June 1942) ni olóṣèlú ará Guinea Ibialágedeméjì tó ti jẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Gínì Ibialágedeméjì láti ọdún 1979. Ó fi ipá gba ìjọba lọ́wọ́ arákùnrin bàbá rẹ̀, Francisco Macías Nguema, nínú ìfipágbàjọba ológun osù kẹjọ ọdún 1979, ó sì ti jẹ́ ààrẹ ibẹ̀ láoti ìgbà náà. Obiang dúró bíi Alága ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà láti 31 January 2011 dé 29 January 2012. Òhun ni ẹnìkejì tó jẹ́ olórí orílẹ̀-èdè tó pẹ́ jùlọ ní orí àga tí kìí ṣe ọba ní àgbáyé.[1] Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Teodoro Obiang Nguema Mbasogo ni a yan ni apejọ apejọ ẹgbẹ rẹ gẹgẹbi oludije fun saa kẹfa ninu idibo 2023.
Teodoro Obiang Nguema Mbasogo | |
---|---|
Obiang in 2008 | |
2nd President of Equatorial Guinea | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 3 Oṣù Kẹjọ 1979 | |
Alákóso Àgbà | Cristino Seriche Bioko Silvestre Siale Bileka Ángel Serafín Seriche Dougan Cándido Muatetema Rivas Miguel Abia Biteo Boricó Ricardo Mangue Obama Nfubea Ignacio Milam Tang Vicente Ehate Tomi Francisco Pascual Obama Asue |
Vice President | Florencio Mayé Elá Vicente Ehate Tomi Teodoro Obiang Mangue |
Asíwájú | Francisco Macías Nguema |
Chairperson of the African Union | |
In office Àdàkọ:Start and end dates | |
Asíwájú | Bingu wa Mutharika |
Arọ́pò | Thomas Boni Yayi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹfà 1942 Acoacán, Spanish Guinea (now Equatorial Guinea) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Àdàkọ:Married |
Àwọn ọmọ | Teodoro Obiang Mangue |
Relatives | Armengol Ondo (brother) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |