Ija Ikonilẹru ti Suðuroy
Ija Ikonilẹru ti Suðuroy jẹ́ ija ti awọn afigba ọkọ oju omi lai ariwaiwọ oorun ilẹ́ Afrika to ṣẹlẹ ni Suðuroy ni Erekusu Faroe ni summer ti ọdun 1629. Eyi lo jasi ijinigbe awọn eniyan ọgbon ti wọn obinrin ati ọmọde ti wọn kogbe ni Etikun ti Barbary ti Ariwa ilẹ Afrika.