Ikare Akoko
Ikarẹ-Àkókó je ilu nla kan ti o wa ni apa guusu iwo-Oorun Ìpílẹ̀ Ondo, Nàìjíríà.[citation needed] Ilu Ikarẹ to ẹgbẹrun ibusọ si ilu Akure ti o jẹ olu ilu fun ipinle Ondo. Ilu yi ni o jẹ olu ilu fun awọn ilu ti o wa ni ẹkun ijọba agbegbe Akoko bi Oka-Akoko, Isua-Akoko, Okeagbe-Akoko, Ugbe Akoko ati bbl. Ilu Ikare-Akoko ni o jẹ olu ilu fun ijoba ibilẹ Akoko North-East Local Government.Awọn ohun ọrọ aje ilu naa ni obì, kòkó àti kọfí.[citation needed]
Ikare-Akoko Ùkàrẹ́ | |
---|---|
Motto(s): ọmọ olókè méjì takọ tabo | |
Coordinates: 7°31′N 5°45′E / 7.517°N 5.750°ECoordinates: 7°31′N 5°45′E / 7.517°N 5.750°E | |
Country | Nigeria |
State | Ondo |
Demonym(s) | omo Ikare |
Ilu Ikare paala pẹlu Arigidi Akoko, Ugbe Akoko, Ọ̀gbàgì Àkoko, Ọka Akoko, Akungba Akoko ati Supare Akoko.
Ọja Osele ni ọja abalaye ti o tobi julọ ninu gbogbo ọja ti o wa ni ilu naa, nigba ti ọja Ọba wa ni adojukọ ile ifowopamọ first bank ti o wa ni ibudokọ Ikarẹ-Akoko. Ilu Ikarẹ jẹ ilu ti o ko gbogbo ẹsin mọra, awọn ẹlẹsin bi ẹsin ẹsin iṣẹṣe, Musulumi ati Christeni. The architectural style of the city incorporates both Portuguese and Arabic styles.[citation needed] The Portuguese style was introduced in the 16th century when Portugal began to export slaves from the region.[1] Arabic influences were incorporated in the 19th century with the diffusion of Islamic culture Southward across the Sahara.[citation needed]Population as of 2006 was over 700,000.[citation needed]
Ẹ tún wo
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Western Africa - The beginnings of European activity". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 June 2021.