Ikedi Godson Ohakim

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Ikedi Ohakim)

Ikedi Godson Ohakim (ojoibi 4 August, 1957) je oloselu omo ile Naijiria ati Gomina Ipinle Imo lati 2007 titi de 2011.

Pius Ikedi Godson Ohakim
Gomina Ipinle Imo
In office
29 May 2007 – 29 May 2011
AsíwájúAchike Udenwa
Arọ́pòRochas Okorocha
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹjọ 1957 (1957-08-04) (ọmọ ọdún 67)
Okohia, Isiala Mbano LGA, Imo State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)