Ilé-ẹjọ́ àgbà
Ilé-ẹjọ́ àgbà tí a tún ma sí Supreme Court of Nigeria (SCN) ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ni ó jẹ́ ilé-ẹjọ́ tí ga jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wà ní ìlú Àbújá.[1][2]
Supreme Court of Nigeria | |
---|---|
Established | Oṣù Kẹ̀wá 1, 1963 |
Location | Three Arms Zone, Abuja, FCT, Nigeria |
Composition method | Presidential nomination with confirmation by the senate |
Authorized by | Constitution of Nigeria |
Judge term length | Life tenure with mandatory retirement at the age of 70 |
Number of positions | 21 |
Website | supremecourt.gov.ng |
Chief Justice of Nigeria | |
Currently | Kudirat Kekere-Ekun |
Since | 22 August 2024 |
Nípa rẹ̀
àtúnṣeWọ́n gbé ilé-ẹjọ́ àgbà kalẹ̀ ní ọdún 1976 lẹ́yìn tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà di ilẹ̀ olómìnira lọ́wọ́ àwọn gẹ́ẹ̀sì àmúnisìn ní ọdún 1963.[3] Ilé-ẹjọ́ àgbà ni wọ́n gbé kalẹ̀ lábẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú òfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n pe ní The Supreme Court in its current form was shaped by the Supreme Court Act of 1990', lábẹ́ abala keje ti ọdún 1999 nínú òfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé-ẹjọ́ ni ilé ẹjọ́ tí òfin rẹ̀ ga jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ìdájọ́ tí wọ́n bá dá níbẹ̀ ni pàpin, ìdájọ́ rẹ̀ ní gbogbo ilé-ẹjọ́ gbogbo tókù gbọ́dọ̀ tẹ̀lé tí òfin rẹ̀ sì múlẹ̀ ṣinṣin lórí wọn, òun nìkan ni òfin rẹ̀ kò mú.[4] Ilé-ẹjọ́ mìíràn tí wọ́n gbé kalẹ̀ láti ma gbọ́ ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ni ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn tí òun náà ma ń gbẹ́jọ́ tàbí ṣe àgbéyẹ̀wò sí ẹjọ́ tí ilé-ẹjọ́ ilé-ẹjọ́ gíga ti Ìpínlẹ̀ bá dá tí ẹjọ́ náà kò sì tẹ́ ẹni tí wọ́n dájọ́ fún lọ́rùn. Irúfẹ́ ẹjọ́ yii ni wọ́n ń pe ní ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn. Lábẹ́ òfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ilé-ẹjọ́ àgbà ti ń pàṣẹ, ilé-ẹjọ́ yii nìkan ni ó ní agbára láti gbọ́ ẹjọ kòtẹ́milọ́rùn láti ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn àti àwọn ẹjọ́ mìíràn láti ilé-ẹjọ́ kékèké tókù.[5]
Agbékalẹ̀ Ilé-ẹjọ́ àgbà
àtúnṣeIlé-ẹjọ́ àgbà ní adájọ́ àgbà Chief Justice of Nigeria àti àwọn ìgbìmọ̀ adájọ́ agbààgba mọ́kànlélógún tí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bá yan sípò náà níbàámu pẹ̀lú àbá àti ìmọ̀ràn National Judicial Council, (NJC)[6][7]pẹ̀lú ìfọwọ́sí àti ìbuwọ́lù ilé aṣòfin àgbà. Awọn tí wọn yóò jẹ́ adájọ́ àgbà nílé ẹjọ́ àgbà gbọ́eọ̀ ní ìwé tí peregedé láti ṣíṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí adájọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà , wọ́n sì tún ti gbọdọ̀ ti pegedé sí ipò adájó agbà yí, ó kéré tán ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ṣáájú àsìkò tí wọ́n ń yàn wọ́n gẹ́gẹ́ bí alṣbàáṣiṣẹ́ fún adájọ́ àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àti adájọ́ àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn alábàáṣiṣẹ́-pọ̀ rẹ̀, wọ́n gbọ́dọ̀ kúrò lórí ipò bí ọjọ́ orí wọn bá ti pe àádọ́rin ọdún , ìyẹn tí ikú kò bá pa ẹnikẹ́ni nínú wọn.[8][9]
Àwọn adájọ́ ilé-ẹjọ́ àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́
àtúnṣeOffice | Name | Term |
Chief Justice | Kudirat Kekere-Ekun | 2013–present |
Associate Justice | John Inyang Okoro | 2013–present |
Associate justice | Uwani Musa Abba Aji | 2018–present |
Associate Justice | M. Lawal Garba | 2020–present |
Associate Justice | Helen M. Ogunwumiju | 2020–present |
Associate Justice | I. M. M. Saulawa | 2020–present |
Associate Justice | Adamu Jauro | 2020–present |
Associate Justice | Tijjani Abubakar | 2020–present |
Associate Justice | Emmanuel A. Agim | 2020–present |
Associate Justice | Haruna Tsammani | 2024–present |
Associate Justice | Moore Adumein | 2024–present |
Associate Justice | Jummai Sankey | 2024–present |
Associate Justice | Chidiebere Uwa | 2024–present |
Associate Justice | Chioma Nwosu-Iheme | 2024–present |
Associate Justice | Obande Ogbuinya | 2024–present |
Associate Justice | Stephen Adah | 2024–present |
Associate Justice | Habeeb Abiru | 2024–present |
Associate Justice | Jamilu Tukur | 2024–present |
Associate Justice | Abubakar Umar | 2024–present |
Associate Justice | Mohammed Idris | 2024–present |
Ẹ tún wo
àtúnṣeSupreme Court Act 1990 Archived 2020-02-19 at the Wayback Machine.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Steer Clear Of Three Arms Zone, Police Warn Nigerian Protesters". Sahara Reporters. 2019-07-18. Retrieved 2020-02-17.
- ↑ Shuaibu, Umar (2014-05-05). "The desecration of the Three Arms Zone". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-17.
- ↑ "Nnamdi Azikiwe: A True National Hero". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-11-16. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ "Legal systems in Nigeria: overview". Practical Law (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-11.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Sokefun, Justus; Njoku, Nduka (2016-03-30) (in en). The Court System in Nigeria: Jurisdiction and Appeals. Rochester, NY. SSRN 2940058. https://papers.ssrn.com/abstract=2940058.
- ↑ "NJC approves appointment of four Supreme Court Justices - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-24. Retrieved 2020-02-17.
- ↑ "NJC approves 4 Supreme Court Justices' appointment | P.M. News". pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-02-17.
- ↑ "Recruitment and Tenure of Supreme Court Justices in Nigeria".
- ↑ "Constitution of the Federal Republic of Nigeria". www.nigeria-law.org.