Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà

(Àtúnjúwe láti Ilé Alàgbà Nàìjíríà)

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin gíga ti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin oníbínibí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. O ní àwọn asò̀fin 109: ìkọ̀ọ̀kan àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́r̀ndínlógójì jẹ́ pípín sí agbèègbè asòfin mẹta tí wón dìbòyàn asòfin kọ̀ọ̀kan; bé̀ẹ̀ sì ni agbè̀gbè olúìlú ìjọba àpapọ̀ náà dìbòyàn asòfin kan pééré.

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà
Coat of arms or logo
Type
Type
bicameral
Leadership
Ahmed Lawan, PDP
since June 6, 2007
Obarisi Ovie Omo-Agege, APC
since Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfa Ọdún 2007
Seats109
Meeting place
Abuja

Awon Arannise Ipinle Naijiria àtúnṣe

 1. Abia
 2. Adamawa
 3. Akwa Ibom
 4. Anambra
 5. Bauchi
 6. Bayelsa
 7. Benue
 8. Borno
 9. Cross River
 10. Delta
 11. Ebonyi
 12. Edo
 13. Ekiti
 14. Enugu
 15. Gombe
 16. Imo
 17. Jigawa
 18. Kaduna
 19. Kano
 1. Katsina
 2. Kebbi
 3. Kogi
 4. Kwara
 5. Lagos
 6. Nasarawa
 7. Niger
 8. Ogun
 9. Ondo
 10. Osun
 11. Oyo
 12. Plateau
 13. Rivers
 14. Sokoto
 15. Taraba
 16. Yobe
 17. Zamfara
 18. Abuja FCT


Àwọn Alàgbà àtúnṣe


Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

Àdàkọ:Oselu ni Naijiria