Ile Gbigbe Mambilla
Ilẹ̀ gbígbe Mamìbíllà wà ní Gémbù, ìjọba ìbílẹ̀ Sáúdánà ní ìpínlẹ̀ Tàrába ní Oríĺ èdè Nàìjìríà. Ile gbigbe yii je itesiwaju arewa orile ede Naijiria ti oke ile okeere Kameruunu. Ó wà ní agbede ìgbéga 1600meters (5,249ft) ìpele odò, tí ó sọ di òkè tí ó ga jù ní orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.[1] Àwọn abúlé tí ó wà ní orí òké náà tí ó ga kéré jù lọ ní 1828 meter (iwon ese bata 5,997) kọjá ìpele odò.
Awọn òkè tí ó yípo ilè gbígbẹ náà ga ní ẹgbẹ̀rún méjì mítà (2,000metres), ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà Ẹ́ẹ́rìn- dín- lọ́gbọ̀n- lé- ̀ẹẹ́dẹ́gbẹ̀ta- lé -lẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6526ft),bíi òkè chapali Waddi tí ó ga ní ìgbede mítà Óókàn- dí- lógún -lenírinwó- lé lẹ́gbẹ̀rún méjì( 2,419meters), ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà Éérìn -dín- lógójì -lé- lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún -lé - lẹ́gbẹ̀rún méje (7,936ft) kọjá ìpele odò. Tí a bá yọ ÒKè kamẹrúùnù kúrò, Màmìbíllà ni òkè tí ó ga jù níorílẹ̀ èdè Nàíjíríà àti Ìwọ̀ òòrùn Áfíríkà.
Ilẹ̀ gbígbe Màmìbílà wọn kìlòmítà Ẹ́ẹ́rìn -dín -lọ́gọ̀rún ní ìparí igun (96km) (60mi); ogójì kìlòmítà ní ìbú (40km) (25mi) , pẹ̀lú ìyípo tí ó ga ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún mítà (900m), ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà ẹ́ẹ́tà lé- láádọ̀ta -lé- lẹ́gbẹ̀rún méjì (2,953ft) . Òkè náà gba agbègbè tí ó lé ní kìlòmítà oníhàmẹ́rin Óókàn -dín̄- lé -láádọ̀rún -lé lọ́ọ́dúrún lé lẹ́ẹ́gbẹ̀rún mésàn. (9389 square kilometer) (3625mi
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe1. "Mambilla Plateau". Wikimapia. Retrieved 2019-11-22.
2.