Ilojo Bar, tí wọ́n tún ń pè ní Ilé Ọláìyá tàbí Casa da Fernández jẹ́ ilé ìṣẹ̀ǹbáyé tí wọ́n kọ́ bí ti àwọn Brazil tí ó wà ní Tinubu Square, Lagos Island, Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . [1] [2]

Àwòrán Ilojo Bar

Orúkọ "Ilojo Bar" àtúnṣe

Lẹ́yìn tí wọ́n tá ilé náà fún Alfred Omolona ní ọdún 1933, o yí orúkọ rẹ dà sí “Ilojo" èyí tí ó jẹ́ orúkọ ìlú rẹ̀ “Ilojo" ní Ìjẹ̀sà Ìṣù ni Ipinle Ekiti. [3]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe