Imamuddin Punjabi
Àdàkọ:Infobox religious biography Abu al-Fadhl Imāmuddīn Khān Barāwli Chhachhrī[1] (tí a tún mò sí Imamuddin Punjabi) (ó kú ní 1916) jé Indian ti mùsùlùmí Sunni onímò ìjìnlè tí ó se olùdásílè Jamia Miftahul Uloom.
Ìtàn Ìdílé
àtúnṣeÀwon asááju Imāmuddīn Punjabi wá láti agbègbè Brawl, Bajaur.[2] Wón ti sí lo sí Chhachh, wón sì se ibùdó won sí Kāla Noor ní agbègbè Batala ní Punjab.[3]
Ìgbésí ayé
àtúnṣeA bí Imāmuddīn Punjabi ní Batala, ìlú kan nínú ìpínlè Punjab[4] ní orílé-èdè India. Ó kó èkó ahādith pèlú Ahmad Ali Saharanpuri[5] tí ó sì parí èkó rè ní ilé-èkó ìbílè ti dars-e-nizami láti Darul Uloom Deoband.[6] Nígbà tí ó parí èkó rè ní ilé-èkó ìmò èsìn ti Deoband, Punjabi se ìpinnú àjosepò pèlú Fazle Rahmān Ganj Murādābādi ní Sufism.[7]
Punjabi sí lo sí Maunath Bhanjan ní 1298 AH.[8] Ó se ìdásílè Jamia Miftahul Uloom, ilé-èkó èsìn ìlú-mòóká ní ìpínlè Uttar Pradesh.[5] ní orílé-èdè India.
Punjabi pa ipò dà ní odún 1916 ní Mau nínú àpapò ìgbèríko United Provinces of Agra and Oudh.[5]
Isé ìwé
àtúnṣeÀgbéjáde àwon ìwé ni ìwònyí:[9]
- al-Balāgh al-Mubīn
- Tab'yīn al-Kalām fi daf' il-Khisām
- Masābīh al-Itlā ala al-Tahrīm al-Tawājud wa al-Simā
- Rabī al-Anwār
- Eīdayn ki namāz ka waqt
Ìwé ìtàn
àtúnṣe- Adrawi, Asīr (in Urdu). Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. Deoria, Uttar Pradesh: Qamr al-Bāri M.Sc..
Àtókasí
àtúnṣe- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 15.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 16.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 17.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. pp. 14, 16.
- ↑ 5.0 5.1 5.2 Asir Adrawi (in Urdu). Tazkirah Mashāhīr-e-Hind: Karwān-e-Rafta (2 April 2016 ed.). Deoband: Darul Muallifeen. pp. 42–43.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. pp. 27–28.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 22.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 33.
- ↑ Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. pp. 68, 71, 76, 79, 82.