Prótókóòlù Íntánẹ́ẹ̀tì
(Àtúnjúwe láti Internet Protocol)
Prótókóòlù Íntánẹ́ẹ̀tì (IP fún Internet Protocol ní èdè gẹ̀ẹ́sì) ni prótókóòlù ìbánisọ̀rọ̀ gígà láàrin àkójọ àwọn prótókóòlù Íntánẹ́ẹ̀tì fún pípolongo àwọn dátágrámù káàkiri àwọn bodè ẹ̀rọ-àsopọ̀. Iṣẹ́ ìtọ́sọ́nà rẹ̀ gba ìse ìso-ẹ̀rọpọ̀ láàyè, èyí ló ṣe ìdásílẹ̀ Íntánẹ́ẹ̀tì.
Àwọn TCP/IP | |
---|---|
Application Layer | |
BGP · DHCP · DNS · FTP · GTP · HTTP · IMAP · IRC · Megaco · MGCP · NNTP · NTP · POP · RIP · RPC · RTP · RTSP · SDP · SIP · SMTP · SNMP · SOAP · SSH · Telnet · TLS/SSL · XMPP · (more) | |
Transport Layer | |
TCP · UDP · DCCP · SCTP · RSVP · ECN · OSPF · (more) | |
Internet Layer | |
IP (IPv4, IPv6) · ICMP · ICMPv6 · IGMP · IPsec · (more) | |
Link Layer | |
ARP/InARP · NDP · Tunnels (L2TP) · PPP · Media Access Control (Ethernet, DSL, ISDN, FDDI) · (more) | |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |