Irène Tassembédo (ti a bi ni ojo kankandilogun osu kejo odun 1956) je onijo, akorin ati osere ti o wa lati orile ede Bùrkínà Fasò.[1]

Irène Tassembédo
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kẹjọ 1957 (1957-08-19) (ọmọ ọdún 67)
Orílẹ̀-èdèBurkina Faso
Iṣẹ́Osere

Igbesiaye

àtúnṣe

O ko ijo ibile titi Ouagadougou, lehin na o ko ijo imusin titi ile Europe, lehin Germaine Acogny, ni ile iwe Mudra Afrique, ti Maurice Bejart da sile ni Dakar[2][3] bbnxnxxmxnmxmmxmx,mxm

Lehin idanileko yi, o ko lo si ilu Europe gegebi onijo, ni awon odun ibere ti 1980,. O man lo si ilu Burkina Faso dada, ati pe o ti se orisisi ikose ni orile ede Orílẹ̀-èdè Ìṣọ̀kan àwọn Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà ati ni Europe. Ni odun 1988 o da Compagnie Ébène ni ilu Parisi, eleyi ni o fi se irin ajo lo si ilu orisirisi lati fi ise e gege bi olorin fi han si awon eyan. O sumo, o si tun ririn ajo pelu egbe Fusion ni odun 1988, ni odun 1989 o rin irin ajo pelu egbe Diminoïda. O ko ipa ninu ipade Caravane d'Afrique Francophone ti o waye ni ilu Paris, ni odun 1991. O bere Yenenga ni ilu Paris, ni osu kewa odun 1992[4] bbbbbb

Ni odun 1993, ohun ati egbe e ririn ajo wa si ipele akoko titi aworan ile Áfríkà ati idani laraya ti o waaye ni ilu Abidjan. O di gbajumo won si yan fun ijo ti o ma n waye ni ododun meji ti ti Lyon, ni odun 1994, okiki re gegebi akorin ati oni ijo tan kakiri. Ni odun 1998 o da Ebène ni Paris. O tun sise pelu ile abinibi e, lehin igba ti won da ajo onijo ballet titi Burkina Faso kale. Gege bi Irene Tassembo se so:"ki oto di igba yen, awon egbe ibile nikan ni o wa. A ko awon onijo lati origun Burkina, gbogbo won ko ijo ti won mo tele."[5]

Awọn itọkasi

àtúnṣe