Burkina Faso

(Àtúnjúwe láti Bùrkínà Fasò)

Bùrkínà Fasò ( /bərˌknə ˈfɑːs/ bər-KEE-nə FAH-soh; Faransé: [buʁkina faso]) – bakanna ni kukuru bi Burkina – je orile-ede àdèmọ́àrinlẹ̀ ni iwoorun Afrika. Awon orile-ede mefa loyi ka: Mali ni ariwa, Niger ni ilaorun, Benin ni guusuilaorun, Togo ati Ghana ni guusu, ati Côte d'Ivoire ni guusuiwoorun. Oluilu re ni Ouagadougou.

Bùrkínà Fasò
Motto: "Unité-Progrès-Justice"
("Ọ̀kan, Ìrewájú, Ìdájọ́")
("Unity, Progress, Justice")
Orin ìyìn: Une Seule Nuit  (Faransé)
Àṣálẹ́ kannáà
One Single Night – Thomas Sankara
Ibùdó ilẹ̀  Burkina Faso  (búlù dúdú) – ní Africa  (búlù amọ́lẹ̀ & àwọ̀-érú dúdú) – in the Ìṣọ̀kan Áfríkà  (búlù amọ́lẹ̀)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Burkina Faso  (búlù dúdú)

– ní Africa  (búlù amọ́lẹ̀ & àwọ̀-érú dúdú)
– in the Ìṣọ̀kan Áfríkà  (búlù amọ́lẹ̀)  —  [Legend]

OlùìlúOuagadougou
Ìlú tótóbijùlọolúìlú
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFaransé
Lílò regional languagesMòoré, Mandinka (Bambara)
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(1995)
Mossi 47.9%
Fulani 10.3%
Lobi 6.9%
Bobo 6.9%
Mande 6.7%
Senufo 5.3%
Grosi 5%
Gurma 4.8%
Tuareg 3.1%
Orúkọ aráàlúara Burkina Faso (tabi Burkinabè ati Burkinabe)
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira oníààrẹ díẹ̀
• Ààrẹ
Ibrahim Traoré
Apollinaire de Tambèla
AṣòfinIlé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
• látọwó Fránsì
5 August 1960
Ìtóbi
• Total
274,200 km2 (105,900 sq mi) (74th)
• Omi (%)
0.146%
Alábùgbé
• 2020 estimate
21,510,181[1] (58th)
• 2006 census
14,017,262
• Ìdìmọ́ra
64/km2 (165.8/sq mi) (137th)
GDP (PPP)2020 estimate
• Total
$45.339 billion
• Per capita
$2,207[2]
GDP (nominal)2020 estimate
• Total
$16.226 billion
• Per capita
$792[2]
Gini (2020)Steady 38.9[3]
medium
HDI (2019) 0.452[4]
low · 182nd
OwónínáWest African CFA franc[5]
Ibi àkókòUTC+0
• Ìgbà oru (DST)
kòsí
Ojúọ̀nà ọkọ́ọ̀tún
Àmì tẹlifóònù226
ISO 3166 codeBF
Internet TLD.bf
  1. The data here is an estimation for the year 2005 produced by the International Monetary Fund in April 2005.

Itobi re je 274,200 square kilometres (105,900 sq mi) pelu awon alabugbe to poju 15,757,000 lo. Teletele oruko re ni Órile-ede Olominira Upper Volta (Republic of Upper Volta), o je titunsoloruko si Burkina Faso ni ojo 4 Osu Kejo 1984, latowo Aare Thomas Sankara, to tumosi "ile awon eniyan anaro" ("the land of upright people") ni awon ede Mòoré ati Dioula, ti won je ede abinibi pataki nibe. "Burkina" le je, "awon eniyan olododo", lede Mòoré, ati "Faso" tumosi "ile baba eni" lede Dioula. Awon to bugbe si Burkina Faso unje pipe ni Burkinabè (play /bərˈknəb/ bər-KEE-nə-bay).

Awon eniyan tedo si Burkina Faso larin odun 14,000 and 5000 SK latowo awon ode asako ni apaariwaiwoorun ibe. Abule oko bere nibe larin odun 3600 and 2600 SK. Ibi to unje arin gbongan Burkina Faso loni nigbana je kiki awon ileoba Mossi. Awon Ileoba Mossi wonyi di ibiabo Fransi ni 1896. Leyin ti o gba ilominira latowo Fransi ni 1960, orile-ede na ri iru orisirisi ijoba ko to di eyi to wa loni, orile-ede olominira oniaare die. Aare re lowo ni Blaise Compaoré.

O je omo-egbe Ìṣọ̀kan Áfríkà, Agbajo awon Orile-ede Saheli ati Sahara, La Francophonie, Agbajo Ifowosowopo Onimale ati Agbajo Olokowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika.

Ìtàn kùtùkùtù

àtúnṣe

Ibi-ile ti a mo loni bi Burkina Faso t je titedo kutukutu, larin odun 14,000 ati 5000 SK, latowo awon ode asako ni apaariwaiwoorun ibe, ti awon ohun amulo won bi ihale, igbele ati oriofa won je wiwari ni 1973 latowo Simran Nijjar. Awon abule pelu awon adako bere ni arin odun 3600 ati 2600 SK. Lori bi awon ipele awon agbe se ri, o da bi pe awon abule na je adurotitisi. Ilo irin, iseamo ati okuta didan gbera larin odun 1500 ati 1000 SK.

Aloku awon Dogo wa kakiri ni Burkina Faso ni awon agbegbe ariwa ati ariwaiwoorun. Nigbakan larin orundun kedogun ati kerindinlogun, awon Dogo kuro ni agbegbe yi lati lo budo si etioke Bandiagara. Nibo miran, awon aloku ogiri giga wa ni guusuiwoorun Burkina Faso (ati ni Côte d'Ivoire), sugbon awon ti won ko won ko ti je didamo.

Loropeni ni okuta aye atijo to nibasepo mo owo wura. Ibe ni Ibi Oso Agbaye akoko ti orile-ede Burkina Faso wa.

Arin gbongan apa Burkina Faso ni opo awon ileoba Mossi, awon to lagbara julo ninu won ni ti Wagadogo (Ouagadougou) ati Yatenga. Awon ileoba wonyi je didasile ni ibere orundun ikerindinlogun latowo awon ajagun.[6]

Láti ilẹ̀àmúsìn dé ìlómìnira

àtúnṣe

Bùrkínà Fasò

àtúnṣe

Ìṣèlú

àtúnṣe

Àwọn agbègbè, ìgbèríko àti ìpínapá

àtúnṣe

Ológun, ọlọ́pàá àtí alábòò

àtúnṣe

Oríilẹ̀yíyà àti ojúọjọ́

àtúnṣe

Òkòwò

àtúnṣe

Ẹ̀yàìlú

àtúnṣe

Ẹ̀kọ́

àtúnṣe


  1. "Archived copy" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2016-12-21. Retrieved 2016-02-18.CS1 maint: archived copy as title". 16 November 2021. 
  2. 2.0 2.1 "Report for Selected Countries and Subjects". 
  3. "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 13 May 2009. Retrieved 1 September 2009. 
  4. Human Development Report 2020 The Next Frontier: Human Development and the Anthropocene. United Nations Development Programme. 15 December 2020. pp. 343–346. ISBN 978-92-1-126442-5. http://hdr.undp.org/sites/default/files/hdr2020.pdf. Retrieved 16 December 2020. 
  5. CFA Franc BCEAO. Codes: XOF / 952 ISO 4217 currency names and code elements Archived 7 April 2014 at the Wayback Machine.. ISO.
  6. Michel Izard, Moogo. L'émergence d'un espace étatique ouest-africain au XVIe siècle