Irène Joliot-Curie
(Àtúnjúwe láti Irene Joliot-Curie)
Irène Joliot-Curie (12 September 1897 – 17 March 1956) je onimo sayensi ara Fransi, ohun ni omobinrin Marie Skłodowska-Curie ati Pierre Curie ati iyawo Frédéric Joliot-Curie. Lokanna mo oko re, Joliot-Curie gba Ebun Nobel fun Kemistri ni 1935 fun iwari won iranna afowose. Eyi so ebi Curie di ebi to ni awon elebun Nobel julo titi doni.[1] Bakanna awon omo mejeji awon Joliot-Curies, Hélène ati Pierre na je onimo sayensi pataki.[2]
Irène Joliot-Curie | |
---|---|
Ìbí | Paris, France | 12 Oṣù Kẹ̀sán 1897
Aláìsí | 17 March 1956 Paris, France | (ọmọ ọdún 58)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | French |
Pápá | Chemistry |
Ibi ẹ̀kọ́ | Sorbonne |
Doctoral advisor | Paul Langevin |
Ó gbajúmọ̀ fún | Transmutation of elements |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize for Chemistry (1935) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Nobel Laureates Facts: 'Family Nobel Laureates'". Nobel Foundation. 2008. Retrieved 2008-09-04.
- ↑ Byers, Nina; Williams, Gary A. (2006). "Hélène Langevin-Joliot and Pierre Radvanyi". Out of the Shadows: Contributions of Twentieth-Century Women to Physics. Cambridge, UK: Cambridge University Press. ISBN 0521821975.