Iris Apatow

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Àdàkọ:Use mdy dates

Iris Apatow
Apatow in 2018
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kẹ̀wá 2002 (2002-10-12) (ọmọ ọdún 22)
Iṣẹ́Òṣèré
Ìgbà iṣẹ́2007–present
Parent(s)Leslie Mann
Judd Apatow
Àwọn olùbátanMaude Apatow (sister)

Iris Apatow ( /ˈæpət/; tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2002 jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn "Arya" nínú eré onípele tí wọ́n ń ṣàfihàn rẹ̀.lórí ìkanì Netflix tí akòrí rẹ̀ ń jẹ́ Love, òun náà ló tún kópa ẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn "Charlotte" nínú eré Knocked Up ati This Is 40.

Ìgba èwe rẹ̀

àtúnṣe

Apatow ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2992,[1][2] Apatow tí ó jẹ́ ọmọ gbajú-gbajà òṣèré Judd Apatow, tí ìyá rẹ̀ Leslie Mann náà sì jẹ́ òṣèré pẹ̀lú. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ niMaude Apatow.[3] Her father's family is Jewish. Her maternal great-grandmother was of Finnish ancestry.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí "Charlotte" nínú eré apanilẹ́rìín Knocked Up, eré tí babá rẹ̀ Judd Apatow darí rẹ̀.[5] Ó tún kópa nínú eré This Is 40. Lára àwọn eré onípele orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán tí ó ti kòpa bí "Arya" ni Love.[6][7]

Àwọn àsàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Note
2007 Knocked Up Charlotte
2009 Funny People Ingrid
2012 This Is 40 Charlotte
2016–2018 Love Arya Hopkins Recurring role
2016 Sausage Party Berry Good Candies / Grape #3 / Coconut milk Voice role

Fọ́rán orin

àtúnṣe
Ọdún Akọ́lé Olórin Ref.
2017 "Sonora" Spendtime Palace [8]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Apatow, Iris (October 12, 2018). "This is 16". Iris Apatow verified Instagram account. Retrieved January 7, 2019. 
  2. Cardoza, Riley (August 2, 2019). "Leslie Mann’s Daughter Iris, 16, Claps Back After Mom Critiques Her Makeup on Instagram: 'A Text Would Have Been Nice'". Us Weekly. Archived from the original on November 2, 2019. https://web.archive.org/web/20191102223030/https://www.usmagazine.com/celebrity-moms/news/leslie-manns-daughter-iris-claps-back-after-mom-critiques-makeup/. Retrieved November 24, 2020. "Mann and Apatow, 51 ... welcomed Maude and Iris in 1997 and 2002, respectively." 
  3. LaPorte, Nicole (2012-08-24). "She's 14, Going on 140 Characters". The New York Times. https://www.nytimes.com/2012/08/26/fashion/maude-apatow-is-growing-up-writing.html?pagewanted=all&_r=0. Retrieved 2019-02-07. 
  4. "Cameron Diazin tähdittämässä komediassa aitoa suomalaista sisua – videohaastattelu". Yle Uutiset (in Èdè Finisi). Retrieved 2019-09-04. 
  5. Zakarin, Jordan (2012-11-20). "Judd Apatow on Casting His Daughters and Their Dramatic Onscreen Arguments". The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/live-feed/judd-apatow-casting-daughters-maude-393408. 
  6. Narasaki, Rosie (2016-02-19). "Is Aria from 'Love' Based on a Real Person? Iris Apatow's Child Star Steals the Whole Show". Bustle. http://www.bustle.com/articles/142780-is-aria-from-love-based-on-a-real-person-iris-apatows-child-star-steals-the-whole. 
  7. Fienberg, Daniel (2016-02-14). "'Love': TV Review". The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/review/love-tv-review-864870. 
  8. Eckardt, Stephanie (2017-07-18). "Stranger Things' Finn Wolfhard Directed a Music Video Starring Himself and Iris Apatow". W. https://www.wmagazine.com/story/finn-wolfhard-iris-apatow-music-video. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Àdàkọ:Judd Apatow

Àdàkọ:Authority control