Iroro Tanshi
Iroro Tanshi (tí a bí ní ọdun 1984 tàbí 1985)[1] jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí ó ní òye lọ́pọ̀lopọ̀ nípa àwọn àdán, ó sì ń kó nípa àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà àdán ní Afrika. Ó wà lára àwọn ọ̀lùdásílẹ̀ Small Mammal Conservation Organisation (SMACON).[2]
Iroro Tanshi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọdún 1984 tàbí 1985 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Conservationist, ecologist |
Employer | University Of Benin Small Mammal Conservation Organisation |
Awards | Whitley Award (2021) Future for Nature Award (2020) |
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Nigerian Biologist wins prestigious international prize for nature conservation - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2020-12-02. Archived from the original on 2023-02-10. Retrieved 2023-02-10.
- ↑ "Iroro Tanshi". Future For Nature (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-12.