Isaac Adako Boro

Olóṣèlú

Major Isaac Jasper Adaka Boro [ti a bi ni ọdún 1938 oṣù september ọjọ́ kewa-ọdún1968 oṣù may ọjọ́ kẹ̀sán ti gbogbo eyan man si "Boro",oje ajijabara , ẹya ijaw ati jagun jagun. oje onise pupo bi oluko,ọlopa,jagun jagun, asoju awon akekọ unifasiti. akeko chemistry ati student union president ni ọgbà unifasiti Nsukka.[1][2] O se iferonuhan nipa aṣilo epo ni ipinle niger delta ti awon ijọba ati awon ẹya enugu nikan loni anfaani si. O ni igbabo wipe ipinle Niger Delta loye ki oni anfaani si ju lo.[3] O dá Niger Delta Volunteer Force ati armed millitia ti o ni awon omo ẹya re ẹya ijaw sile. Won ṣe ipolongo Niger Delta Republic ni ọsù february ọdún 1996 ọjọ́ meta le lo logún, won si ba awon federal forces ja fún ọjọ́ mejila ti won o si yege bo . Oun ati awon ẹmẹwa rẹ si ṣewon fun ija ti won ja . General Yakubu Gowon si fun 0un nikan ni iyonda ninu ẹwon.O si lọ fún ipò major ni Nigerian army ti a si fun ni ipo na. Oja fun ijoba titi ti o fi ku ni Ogu Okrika ni ipinle Rivers ti a si mo oun ti o fa iku re titi di oni oloni.[4][5]

Isaac Adaka Boro
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1938-09-10)10 Oṣù Kẹ̀sán 1938
Oloibiri, British Nigeria
Aláìsí9 May 1968(1968-05-09) (ọmọ ọdún 29)
Ogu, Okrika, Rivers State, Nigeria
Àwọn ọmọDeborah Waritimi, Esther Boro, Felix Boro
ProfessionPolitical activist, soldier

Awon ajijagbara ni ipinle Niger Delta bi Ken Saro-Wiwa, Mujahid Dokubo-Asari ati bee bee lọ man ri bi ipo olutọsọọna ti ose fi ọwọ rọ

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Nínú ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀ tó kọ fúnrarẹ̀, tó pè ní "The Twelve-Day Revolution", ó kọ nípa ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀:[6]

"Mo gbọ́ láti ẹnu ẹ̀rí tó dájú pé wọ́n bí mi ní òru ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹsàn-án ọdún 1938, ní ìlú Olobiri, ní Niger Delta. Bàbá mi jé ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé kan ṣoṣo níbẹ̀. Kí n tó gbọ́njú mọ àyíká mi dáadáa, mo ti wà ní Port Harcourt níbi tí bàbá mi tún jẹ́ ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé mìíràn. Agbègbè kejì tí mo rántí ni ìlú mi, Kaiama. Wọ́n tún rán bàbá mi lọ bẹ̀ láti jẹ́ ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé mìíràn."

Ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Sola Odunfa (14 February 2006). "Nigeria: Burning with rage". Focus on Africa Magazine (BBC World Service). http://www.bbc.co.uk/worldservice/africa/features/focus_magazine/news/story/2006/05/060515_nigeriadelta.shtml. 
  2. Sanya Osha (1 April 2006). "Birth of the Ogoni Protest Movement" (in en). Journal of Asian and African Studies 41 (1–2): 13–38. doi:10.1177/0021909606061746. ISSN 0021-9096. 
  3. "Niger Delta Avengers threaten return, vow to crash economy". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 27 June 2021. Archived from the original on 6 March 2022. Retrieved 10 March 2022. 
  4. "Fifty-two resounding salutes to Major Isaac Jasper Adaka (Lion) Boro". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 21 May 2020. Retrieved 18 March 2022. 
  5. HistoryVille (7 March 2022). "Isaac Adaka Boro (1938-1968): Nigeria's First Secessionist – HistoryVille" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 August 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  6. "The Twelve-Day Revolution, Chapter 1 - My Early Life'". Archived from the original on 20 April 2015. Retrieved 13 April 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)