Niger Delta
Niger Delta jẹ́ ilẹ̀ àti iyẹ̀pẹ̀ tí ó sàn láti Odò Ọya tí ó sì wà ni Gulf of Guinea ti Atlantic Ocean, Nàìjíríà.[1][2] Ó wà lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà.
Ọ̀pọ̀lopọ̀ lọ ń gbé lórí Niger Delta, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì mọ ibè sí Oil Rivers nítorí ibè ni wọ́n ti ń ṣe epo Pupa ní Nàìjíríà.[3] Ibẹ̀ náà sì jẹ́ ibi tí ọ̀pọ̀lopọ̀ epo rọ̀bì.[4][5]
Ilẹ̀ Niger Delta
àtúnṣeNiger Delta ní ilẹ̀ tí ó tó 70,000 km2 (27,000 sq mi), ó sì gbà tó 7.5% gbogbo ilẹ̀ Nàìjíríà. Àwọn Ìpínlẹ̀ tí ilẹ̀ náà dé ni Bayelsa, Delta, àti Ìpínlẹ̀ Rivers. Niger Delta ló pín Bight of Benin àti Bight of Bonny níyà nínú Gulf of Guinea.[6]
Àwọn ènìyàn tí ó tó mílíọ̀nù ókànlélógbọ̀n ni ó gbé ní Niger Delta[7] àwọn ẹ̀yà tí ó wà níbè sì tó ogójì, àwọn ẹ̀yà bi Ukwuani, Abua, Bini, Ohaji/Egbema, Itsekiri, Efik, Esan, Ibibio, Annang, Oron, Ijaw, Igbo, Isoko, Urhobo, Kalabari, Yoruba, Okrika, Ogoni, Ogba–Egbema–Ndoni, Epie-Atissa àti Obolo, wọ́n sì ń sọ èdè tí ó tó ọ́ta-din-lẹwá-lé-nígba(250). Díè nínú àwọn èdè yìí ni èdè Ijaw, Ibibio-Efik, Igboid, Itsekiri, Central Delta, Edoid, àti Àwọn èdè irú Yorùbá,
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ C. Michael Hogan, "Niger River", in M. McGinley (ed.), Encyclopedia of Earth Archived 2013-04-20 at the Wayback Machine., Washington, DC: National Council for Science and Environment, 2013
- ↑ Umoh, Unyime U.; Li, Li; Wang, Junjian; Kauluma, Ndamononghenda; Asuquo, Francis E.; Akpan, Ekom R. (August 2022). "Glycerol dialkyl glycerol tetraether signatures in tropical mesotidal estuary sediments of Qua Iboe River, Gulf of Guinea". Organic Geochemistry 170: 104461. Bibcode 2022OrGeo.17004461U. doi:10.1016/j.orggeochem.2022.104461.
- ↑ Otoabasi, Akpan (2011). The Niger Delta Question and the peace plan. Spectrum Books.
- ↑ 4.0 4.1 Aghalino, S.O (2004). Combating the Niger Delta Crisis: an appraisal of Federal Government response to Anti-Oil protect in Niger Delta, 1958-2002.. Maiduguri journal of Historical studies.
- ↑ Dakolo, Bubaraye (2021). The Riddle of the Oil Thief. Lagos: Purple Shelves. pp. 117–170. ISBN 9789789889907.
- ↑ Akpan, D. (2006). Oil Exploration and environmental degradation in the Niger Delta. A paper presented at the first regional conference..
- ↑ CRS Report for Congress, Nigeria: Current Issues. Updated 30 January 2008.