Ise Forest Reserve jẹ́ igbó tí ó wà lábẹ́ ààbò ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkìtì, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ilẹ̀ igbó náà fẹ̀ tó 142 km2 níye.[1] Nígbàtí ilẹ̀ igbó náà ga ní déédé 366 sí ibi tí omi wà nínú ilẹ̀.[2]

Rachel Ikemeh in the reserve

Nínú ìgbà yí, àwọn ẹ̀yà labalaba tí wọ́n tó 661 ni wọ́n wà níbẹ̀.[3] Nígbà tí igbó yí sì tún jẹ́ ibùgbé fún àwọn ogunlọ́gọ̀ ìnàkí.[4]

Àwọn itọ́kasí

àtúnṣe
  1. World Database on Protected Areas[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Ise Forest Reserve forest reserve, Ondo, Nigeria". ng.geoview.info. Archived from the original on 2023-05-08. Retrieved 2020-11-16. 
  3. Orimaye, Jacob Olufemi; Odunayo Ogunyemi, Olumide; Okosodo, Ehi Francis; Ojo, Victor Abiodun; Agbelusi, Tejumola Olayinka (2016-10-09). "Butterfly Species Diversity in Protected and Unprotected Habitat of Ise Forest Reserve, Ise Ekiti, Ekiti State". Advances in Ecology (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-16. 
  4. Ogunjemite, B. G.; Afolayan, T. A.; Agbelusi, E. A. (2005). "Habitat structure of chimpanzee community in Ise-Forest Reserve, Ekiti State, South-western Nigeria" (in en). African Journal of Ecology 43 (4): 396–399. doi:10.1111/j.1365-2028.2005.00596.x. ISSN 1365-2028. https://onlinelibrary.wiley.com/doi/abs/10.1111/j.1365-2028.2005.00596.x.