Ishaku Abbo

Oloselu Naijiria

Ishaku Elisha Abbo (tí a bí ní Mubi North, Nàìjíríà) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni Sénátọ̀ tí ó ń ṣe aṣojú àgbègbè Adamawa North Senatorial District ní Ìpínlẹ̀ Adamawa.[2][3] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress (APC) lọ́wọ́ lọ́wọ́.[4]

Ishaku Abbo
Sénátọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 June 2019
AsíwájúBinta Masi Garba
ConstituencyAdamawa North
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Ishaku Elisha Abbo
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress APC
ProfessionPolitician
Nickname(s)SIA

Ipa rẹ̀ nínú òsèlú

àtúnṣe

Ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 2019, wọ́n yan Abbo gẹ́gẹ́ bi Sénátọ̀ tí ó ń sójú agbègbè apá àríwá Adamawa, iye àwọn tí ó dìbò fun tó 79,337.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Feminist forum berates Remi Tinubu over alleged comments on Abbo". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-11. Archived from the original on 2022-02-21. Retrieved 2022-02-21. 
  2. "Northern Nigeria’s only female senator loses seat to newcomer". The Punch. 
  3. Garba, Tom. "Senator/Reps of Northern Adamawa zone have lost out to PDP". Nigeria Tribune. Archived from the original on 2 March 2019. Retrieved 25 February 2019. 
  4. "Senator Elisha Ishaku Abbo dumps PDP for APC". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-25. Retrieved 2020-12-06.