Ishmael Reed
Ishmael Scott Reed (ojoibi 22 February 1938) je akoewi ara Amerika, alaroko, ati alaloaroso. Eni pataki onimookomooka omo Afrika Amerika, Reed gbajumo fun awon iwe oniyeye re un ta asa amerika laya, o si un toka si ituje oloselu ati asa re.[1]
Ishmael Reed | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | Ishmael Scott Reed 22 Oṣù Kejì 1938 Chattanooga, Tennessee, U.S. |
Iṣẹ́ | Poet, essayist, novelist |
Ẹ̀kọ́ | University of Buffalo |
Website | |
http://www.ishmaelreed.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |