Ita Enang
Olóṣèlú
Ita Enang (bí ní ojọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ Ọdún 1962) jẹ́ olùrànlọ́wọ́ àgbà fún Ààrẹ Muhammadu Buhari lórí ọ̀rọ̀ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin. Ó jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Itu àti Ibiono Ibom, Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré ti ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọdún 1999 sí 2011.[1][2] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015.[3]
Ita Solomon Enang | |
---|---|
Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
In office Oṣù karún ọdún 1999 – Oṣù karún ọdún 2011 | |
Constituency | Ibiono Ibom (Akwa Ibom) |
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
In office Oṣù karún ọdún 2011 – Oṣù karún ọdún 2015 | |
Asíwájú | Effiong Dickson Bob |
Constituency | Àríwá-ìwọ oòrùn Akwa Ibom |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kẹjọ 1962 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
Occupation | Agbẹjọ́rò |
Website | http://www.itaenanglaw.com/ |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Olufemi Soneye. "Hon. Enang Ita Solomon". African Searchlight. Retrieved 2011-05-03.
- ↑ "HON. ITA SOLOMON JAMES ENANG". The House of Representatives. Retrieved 2011-05-03.
- ↑ "AKWA-IBOM HOUSE OF ASSEMBLY ELECTION: PDP Wins 25 Out Of 26 Seats". PM News. Apr 29, 2011. Retrieved 2011-05-03.