Iyeoka Okoawo ( /ˈjkə/) (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1975) jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè America, akéwì (nípa ohun-ìní ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà) agbórinkalẹ̀, ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọ-nìyàn, olùkọ́ni àti ọmọ-ẹgbẹ́ TEDGlobal Fellow.[1] Irúfẹ́ àwọn orin tí ó máa ń kọ ni soul, R&B, rock, hip hop, àti jazz.

Iyeoka
Background information
Orúkọ àbísọIyeoka Ivie Okoawo
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹrin 1975 (1975-04-28) (ọmọ ọdún 49)
Boston, Massachusetts, United States
Irú orinNeo soul, R&B, soul, funk, hip hop
Occupation(s)Singer-songwriter, poet, educator
InstrumentsVocals, tambourine
Years active1996–present
LabelsUnderground Sun, Phanai Media Group
Associated actsThe Rock By Funk Tribe
Websiteiyeoka.com

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Fellows | Meet the TED Fellows | TEDGlobal 2010 Fellows". TED. Retrieved January 18, 2011.