Iza
Isabela Cristina Correia de Lima Lima (ọjọ́ ìbí: Ọwẹwẹ 3, 1990), tí à mọ̀ nípasẹ̀ orúkọ ìpele rẹ̀, IZA, jẹ́ akọrin ti ìlú Brazil, to tún jẹ́ akọrin ati onijo, to dide gba òkìkí láti ìkọ́ orin ti àwọn akọrin biì Beyoncé, Rihanna, ati Sam Smith lori ètò YouTube ẹ. Ó tún tí fi àwọn orin rẹ̀ sórí Spotify àti SoundCloud . Ní òṣù Èbibi 2016, o fọ́wọ́ síwe àdéhùn pẹ̀lú Warner Music Brasil . Álúbọ́ọ̀mù àkọ́kọ́ rẹ̀, Dona de Mim, jáde ní 2018 àti ó tún gbé yiyan kà Latin Grammy Award fun "Best Portuguese Language Contemporary Pop Album" ní ọdún yẹn.
IZA | |
---|---|
IZA ní 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Isabela Cristina Correia de Lima Lima[1] 3 Oṣù Kẹ̀sán 1990 Rio de Janeiro, Brasil |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2016–èní |
Ọmọ ìlú | Natal, Rio Grande do Norte, Brasil |
Olólùfẹ́ | Sérgio Santos (m. Àsìṣe: àsìkò àìtọ́) |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments |
|
Labels | Warner Music Brasil[2] |
Associated acts | |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedfull name
- ↑ "Dona de voz poderosa, a cantora Iza é novo nome do pop nacional". Vip. Retrieved 2016-01-18.